Fri May 17 2019 08:29:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 08:29:20 +01:00
parent 5ef578ae37
commit d0a3d6e035
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Ṣùgbọ́n ègbé ni fún àwọn tó gbé ọmọ àti àwọn tó ńtọ́jú ọmọ ọwọ́ ní àwọn ọjọ́ náà. \v 18 Ẹ gbàdúra pe kí èyí má ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹrùn. \v 19 Nítorí ìpọ́njú ńlá yio wà, irú èyí tí kò ti i ṣẹlẹ̀ ri láti ìbẹ̀rẹ̀, ti Ọlọ́run dá ayé, títí di òní, rárá, tàbí yio tùń ṣẹlẹ̀ mọ́. \v 20 Àyàfi bí Olúwa bá dín ọjọ́ náà kù, kò sí ẹni tí yíó yè. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn àyànfẹ́, àwọn tí ó yàn, ó gé àwọn ọjọ́ náà kúrú.
\v 17 Ṣùgbọ́n ègbé ni fún àwọn tó gbé ọmọ àti àwọn tó ńtọ́jú ọmọ ọwọ́ ní àwọn ọjọ́ náà. \v 18 Ẹ gbàdúra pe kí èyí má ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn. \v 19 Nítorí ìpọ́njú ńlá yóò wà, irú èyí tí kò ti i ṣẹlẹ̀ ri láti àsìkò, ti Ọlọ́run dá ayé, títí di òní, rárá, tàbí tí yóò tùń ṣẹlẹ̀ mọ́. \v 20 Àyàfi bí Olúwa bá dín ọjọ́ náà kù, kò sí ẹni tí yóò yè. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn àyànfẹ́, àwọn tí ó yàn, ó ti gé àwọn ọjọ́ náà kúrú.

View File

@ -43,6 +43,7 @@
"13-09",
"13-11",
"13-14",
"13-17",
"13-21",
"13-24",
"13-28",