diff --git a/13/17.txt b/13/17.txt index f64ba48..6e15c2d 100644 --- a/13/17.txt +++ b/13/17.txt @@ -1 +1 @@ -\v 17 Ṣùgbọ́n ègbé ni fún àwọn tó gbé ọmọ àti àwọn tó ńtọ́jú ọmọ ọwọ́ ní àwọn ọjọ́ náà. \v 18 Ẹ gbàdúra pe kí èyí má ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹrùn. \v 19 Nítorí ìpọ́njú ńlá yio wà, irú èyí tí kò ti i ṣẹlẹ̀ ri láti ìbẹ̀rẹ̀, ti Ọlọ́run dá ayé, títí di òní, rárá, tàbí yio tùń ṣẹlẹ̀ mọ́. \v 20 Àyàfi bí Olúwa bá dín ọjọ́ náà kù, kò sí ẹni tí yíó yè. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn àyànfẹ́, àwọn tí ó yàn, ó gé àwọn ọjọ́ náà kúrú. \ No newline at end of file +\v 17 Ṣùgbọ́n ègbé ni fún àwọn tó gbé ọmọ àti àwọn tó ńtọ́jú ọmọ ọwọ́ ní àwọn ọjọ́ náà. \v 18 Ẹ gbàdúra pe kí èyí má ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn. \v 19 Nítorí ìpọ́njú ńlá yóò wà, irú èyí tí kò ti i ṣẹlẹ̀ ri láti àsìkò, ti Ọlọ́run dá ayé, títí di òní, rárá, tàbí tí yóò tùń ṣẹlẹ̀ mọ́. \v 20 Àyàfi bí Olúwa bá dín ọjọ́ náà kù, kò sí ẹni tí yóò yè. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn àyànfẹ́, àwọn tí ó yàn, ó ti gé àwọn ọjọ́ náà kúrú. \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index e282899..1f4a500 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -43,6 +43,7 @@ "13-09", "13-11", "13-14", + "13-17", "13-21", "13-24", "13-28",