Fri May 17 2019 08:27:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 08:27:20 +01:00
parent aa5fbd49fd
commit 5ef578ae37
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Ṣùgbọ́n ègbé ni fún àwọn tó ọmọ àti àwọn tó ńtọ́jú ọmọ ọwọ́ ní àwọn ọjọ́ náà. \v 18 Ẹ gbàdúra pe kí ó má ṣẹlẹ̀ nígbà ẹ̀rùn. \v 19 Nítorí ìpọ́njú ńlá yio wà, irú èyí tí kò ti i ṣẹlẹ̀ ri láti ìbẹ̀rẹ̀, ti Ọlọ́run dá ayé, títí di òní, rárá, tàbí yio tùń ṣẹlẹ̀ mọ́. \v 20 Àyàfi bí Olúwa bá dín ọjọ́ náà kù, kò sí ẹni tí yíó yè. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn àyànfẹ́, àwọn tí ó yàn, ó gé àwọn ọjọ́ náà kúrú.
\v 17 Ṣùgbọ́n ègbé ni fún àwọn tó gbé ọmọ àti àwọn tó ńtọ́jú ọmọ ọwọ́ ní àwọn ọjọ́ náà. \v 18 Ẹ gbàdúra pe kí èyí má ṣẹlẹ̀ ní ìgbà ẹ̀ẹrùn. \v 19 Nítorí ìpọ́njú ńlá yio wà, irú èyí tí kò ti i ṣẹlẹ̀ ri láti ìbẹ̀rẹ̀, ti Ọlọ́run dá ayé, títí di òní, rárá, tàbí yio tùń ṣẹlẹ̀ mọ́. \v 20 Àyàfi bí Olúwa bá dín ọjọ́ náà kù, kò sí ẹni tí yíó yè. Ṣùgbọ́n nítorí àwọn àyànfẹ́, àwọn tí ó yàn, ó gé àwọn ọjọ́ náà kúrú.