Thu May 16 2019 15:24:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:24:35 +01:00
parent 7286f79820
commit 02457f34f5
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kíló dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?"
\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kí ni ó dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?"

View File

@ -1 +1 @@
\v 25 Ó sì wí fun wọn pé, "Ẹ̀yin kò tí ka ohun tí Dáfídì se nígbàtí ó se aálaìní tí ebí sì npa á- oun pẹ̀lú àwọn okùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ- \v 26 bí ó ti wọ ilé Ọlọ́run nígbàtí Ábíátárì nse olú àlùfáà, ó sì jẹ àkàrà pẹpẹ, èyí tí kò bá òfin mu fún ẹnikẹ́ni láti jẹ ẹ̀ àfi àwọn àlùfáà, ó sì tún fi fún àwọn tí ó wà pẹ̀lú u rẹ̀.?"
\v 25 Ó sì wí fun wọn pé, "Ẹ̀yin kò tí ka ohun tí Dáfídì se nígbàtí ó se aálaìní tí ebí sì npa á,- oun pẹ̀lú àwọn okùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ- \v 26 bí ó ti wọ ilé Ọlọ́run nígbàtí Ábíátárì nse olú àlùfáà, ó sì jẹ àkàrà pẹpẹ, èyí tí kò bá òfin mu fún ẹnikẹ́ni láti jẹ àfi àwọn àlùfáà, ó sì tún fi fún àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀.?"

View File

@ -36,7 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-25",
"02-27"
]
}