Thu May 16 2019 15:23:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:23:10 +01:00
parent 5986e362c8
commit 7286f79820
4 changed files with 3 additions and 5 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 20 Sùgbọ́n ọjọ́ nbọ nígbàtí a o mu ọkọ ìyàwó kúrò lọ́dọ̀ wọn, nígbàyí, wọn yio gbàwẹ̀. \v 21 Kòsí enìkan tí nran aṣọ titun mọ́ ẹwu tí ó ti gbó, bíbẹ́ẹ̀kọ́, aṣọ titun tí a rán yio ya kúrò lára tàtijọ́, yio si ya ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.
\v 20 Sùgbọ́n ọjọ́ nbọ nígbàtí a o mu ọkọ ìyàwó kúrò lọ́dọ̀ wọn, nígbàyí, wọn yio gbàwẹ̀. \v 21 Kòsí enìkan tí nran aṣọ titun mọ́ ẹwu tí ó ti gbó, bíbẹ́ẹ̀kọ́, aṣọ titun tí a rán yio ya kúrò lára ti àtijọ́, yio si ya ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.

View File

@ -1 +1 @@
\v 22 Kòsí enìkan tí nfi wáìnì titun sínú awọ wáìnì àtijọ́, bíkòsebẹ wáìnì náà yio bẹ́ awọ ti wáìnì àti awọ wáìnì yio sì sègbé pọ̀. Dípòo bẹ́ẹ̀, fi wáìnì titun sínú awọ wáìnì titun."
\v 22 Kòsí nìkan tí nfi wáìnì titun sínú awọ wáìnì àtijọ́, bíkòsebẹ wáìnì náà yio bẹ́ awọ ti wáìnì àti awọ wáìnì yio sì sègbé pọ̀. Dípòo bẹ́ẹ̀, fi wáìnì titun sínú awọ wáìnì titun."

View File

@ -1 +1 @@
\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsi, kíló dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?"
\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kíló dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?"

View File

@ -36,8 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-22",
"02-23",
"02-25",
"02-27"
]