Thu May 16 2019 15:21:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:21:10 +01:00
parent b8c6c1092e
commit 5986e362c8
4 changed files with 3 additions and 7 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 Ó sì tún jáde lẹ́ba omi adágún kan, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó sì kọ́ wọn. \v 14 Bí Ó sì ti nkọjá lọ, Ó rí Lefi ọmọ Álféusì ti o joko ni àgọ́ agbowó òde, Ó sì wí fun pe, "Tọ̀ mí lẹ́yìn." Ó dìde, ó sì tọ lẹ́yìn.
\v 13 Ó sì tún jáde lẹ́ba omi adágún kan, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó sì kọ́ wọn. \v 14 Bí Ó sì ti nkọjá lọ, Ó rí Lefi ọmọ Álféusì ti o joko ni àgọ́ agbowó òde, Ó sì wí fún un pé, "Tọ̀ mí lẹ́yìn." Ó dìde, ó sì tọ lẹ́yìn.

View File

@ -1 +1 @@
\v 15 Jésù si njẹun nínú ilé Lefi àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ wọn ba a jẹun pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sí wà níbẹ̀, wọ́n si ntọ lẹ́yìn. \v 16 Nígbàtí àwọn akọ̀wé, ti wọn jẹ́ Farisí, rí tí Jésù njẹun pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́sẹ̀ àti àwọn agbowó òde, wọ́n wí fún àwon ọmọ ẹ̀yìn rẹ pe, "Kíló sẹlẹ̀ tí O nfi bá àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ̀ jẹun?"
\v 15 Jésù si njẹun nínú ilé Lefi àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ, wọn ba a jẹun pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sí wà níbẹ̀, wọ́n si ntọ lẹ́yìn. \v 16 Nígbàtí àwọn akọ̀wé, ti wọn jẹ́ Farisí, rí tí Jésù njẹun pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́sẹ̀ àti àwọn agbowó òde, wọ́n wí fún àwon ọmọ ẹ̀yìn rẹ pe, "Kíló sẹlẹ̀ tí O nfi bá àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ̀ jẹun?"

View File

@ -1 +1 @@
\v 18 Ó sì se àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí ngba àwẹ̀. Àwọn ènìyàn kan wá wọ́n sì wí fún pe, "Kíló dé tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí fi ngbawẹ, sùgbọ́n àwọn ọmọ ẹ̀yín rẹ ko gbàwẹ̀?" \v 19 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ó seése kí àwọn tì ó wá sí ibi ìgbéyàwó ma gbàwẹ̀ nígbàtí ọkọ ìyàwó sì wà pẹ̀lú wọn?" Níwọ̀n ìgbàtí wọn bá sì ní ọkọ ìyàwó larin wọn, kò seése fún wọn lati gbàwẹ̀.
\v 18 Ó sì se, àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí ngba àwẹ̀. Àwọn ènìyàn kan wá, wọ́n sì wí fún pe, "Kíló dé tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí fi ngbawẹ, sùgbọ́n àwọn ọmọ ẹ̀yín rẹ ko gbàwẹ̀?" \v 19 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ó seése kí àwọn tì ó wá sí ibi ìgbéyàwó ma gbàwẹ̀ nígbàtí ọkọ ìyàwó sì wà pẹ̀lú wọn?" Níwọ̀n ìgbàtí wọn bá sì ní ọkọ ìyàwó larin wọn, kò seése fún wọn lati gbàwẹ̀.

View File

@ -36,10 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-15",
"02-17",
"02-18",
"02-20",
"02-22",
"02-23",
"02-25",