Thu May 16 2019 15:19:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:19:10 +01:00
parent 4fa4639388
commit b8c6c1092e
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó le mọ̀ wípé Ọmọ ènìyàn ní àsẹ ní aiyé lati dárí ẹ̀sẹ̀ jìn" Ó wí fún ẹnití ó rọ náà, \v 11 "mo wí fún ọ, dìde, gbé ení rẹ, kí o sì ma lọ sí ilé rẹ." \v 12 Ó dìde lójú ẹsẹ́, ó sì gbé ení rẹ, ó sì jáde kúrù ninú ilé náà lójú gbogbo ènìyàn, tóbẹ̀ tí ẹnu sì ya gbogbo wọn tí wọ́n sì fi ògo fún Ọlọ́run, wọ́n sì wípé, "A kò rí irú èyí rí rárá."
\v 10 Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó le mọ̀ wípé Ọmọ ènìyàn ní àsẹ ní ayé lati dárí ẹ̀sẹ̀ jìn" Ó wí fún ẹnití ó rọ náà, \v 11 "mo wí fún ọ, dìde, gbé ení rẹ, kí o sì ma lọ sí ilé rẹ." \v 12 Ó dìde lójú ẹsẹ́, ó sì gbé ení rẹ, ó sì jáde kúrò ninú ilé náà lójú gbogbo ènìyàn, tóbẹ̀ tí ẹnu sì ya gbogbo wọn, tí wọ́n sì fi ògo fún Ọlọ́run, wọ́n sì wípé, "A kò rí irú èyí rí rárá."

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 Ó sì tún jáde lẹ́ba omi adágún kan, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ rẹ, Ó sì kọ́ wọn. \v 14 Bí Ó sì ti nkọjá lọ, Ó rí Lefi ọmọ Alfeusi ti o joko ni àgọ́ agbowó òde, Ó sì wí fun pe, "Tọ̀ mí lẹ́yìn." Ó dìde, ó sì tọ lẹ́yìn.
\v 13 Ó sì tún jáde lẹ́ba omi adágún kan, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó sì kọ́ wọn. \v 14 Bí Ó sì ti nkọjá lọ, Ó rí Lefi ọmọ Álféusì ti o joko ni àgọ́ agbowó òde, Ó sì wí fun pe, "Tọ̀ mí lẹ́yìn." Ó dìde, ó sì tọ lẹ́yìn.

View File

@ -36,7 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-13",
"02-15",
"02-17",
"02-18",