Thu May 16 2019 15:17:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:17:10 +01:00
parent 186d10b95d
commit 4fa4639388
4 changed files with 3 additions and 5 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Jésù rí ìgbàgbọ́ wọn, Ó sì wí fún ọkùnrin arọ náà pé, "Ọmọkùnrin, a fi gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́" \v 6 Àwọn akọ̀wẹ́ sì joko síbẹ̀, wọ́n sì nrò nínú ọkàn wọn \v 7 Bawo ni ọkùnrin yi ti nsọ̀rọ̀ bayi? O nsọ̀rọ̀ òdì! Tani ẹni náà tí ó le fi ẹ̀sẹ̀ jìn bíkòse Ọlọ́run nìkan?"
\v 5 Jésù rí ìgbàgbọ́ wọn, Ó sì wí fún ọkùnrin arọ náà pé, "Ọmọkùnrin, a fi gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́" \v 6 Àwọn akọ̀wé sì joko síbẹ̀, wọ́n sì nrò nínú ọkàn wọn: \v 7 "Bawo ni ọkùnrin yi ti nsọ̀rọ̀ bayi? O nsọ̀rọ̀ òdì! Tani ẹni náà tí ó le fi ẹ̀sẹ̀ jìn bíkòse Ọlọ́run nìkan?"

View File

@ -1 +1 @@
\v 8 Lójú ẹsẹ́ Jésù mọ ohun tí wọn nrò larin ara wọn nínú ọkàn rẹ. Ó wí fún wọn, "Kílódé tí ẹ̀yín fi nro èyí nínú ọkàn yin?" \v 9 Èwo ni ó rorùn jù láti wí fún ọkùnrin tí ó rọ náà, 'A dárí gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́' tàbí lati wípé 'Dìde, gbé ibùsùn rẹ kí o sì ma rìn?'
\v 8 Lójú ẹsẹ́ Jésù mọ ohun tí wọn nrò láàrin ara wọn nínú ọkàn rẹ. Ó wí fún wọn, "Kílódé tí ẹ̀yín fi nro èyí nínú ọkàn yin?" \v 9 Èwo ni ó rorùn jù láti wí fún ọkùnrin tí arọ náà, 'A dárí gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́' tàbí lati wípé 'Dìde, gbé ibùsùn rẹ kí o sì ma rìn?'

View File

@ -1 +1 @@
\v 10 Sùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó le mọ̀ wípé Ọmọ ènìyàn ní àsẹ ní aiyé lati dárí ẹ̀sẹ̀ jìn" Ó wí fún ẹnití ó rọ náà, \v 11 "mo wí fún ọ, dìde, gbé ení rẹ, kí o sì ma lọ sí ilé rẹ." \v 12 Ó dìde lójú ẹsẹ́, ó sì gbé ení rẹ, ó sì jáde kúrù ninú ilé náà lójú gbogbo ènìyàn, tóbẹ̀ tí ẹnu sì ya gbogbo wọn tí wọ́n sì fi ògo fún Ọlọ́run, wọ́n sì wípé, "A kò rí irú èyí rí rárá."
\v 10 ùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó le mọ̀ wípé Ọmọ ènìyàn ní àsẹ ní aiyé lati dárí ẹ̀sẹ̀ jìn" Ó wí fún ẹnití ó rọ náà, \v 11 "mo wí fún ọ, dìde, gbé ení rẹ, kí o sì ma lọ sí ilé rẹ." \v 12 Ó dìde lójú ẹsẹ́, ó sì gbé ení rẹ, ó sì jáde kúrù ninú ilé náà lójú gbogbo ènìyàn, tóbẹ̀ tí ẹnu sì ya gbogbo wọn tí wọ́n sì fi ògo fún Ọlọ́run, wọ́n sì wípé, "A kò rí irú èyí rí rárá."

View File

@ -36,8 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-08",
"02-10",
"02-13",
"02-15",
"02-17",