Thu May 16 2019 15:15:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:15:10 +01:00
parent ddc1e5bd19
commit 186d10b95d
3 changed files with 2 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Nígbànáà ni àwọn ọkùnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ. wọ́n gbe ọkùnrin arọ kan; mẹ́rin ló gbé e. \v 4 Nígbàtí wọ́n kò sì le dé ọ̀dọ̀ rẹ nítorí ọ̀pọ́ ènìyàn, wọ́n sí òrùlé ibi tí Jésù wa, lẹ́yìn èyí ni wọ́n rí yè, wọ́n sì sọ ibùsùn tí ọkùnrin tí arọ náà sùn sí.
\v 3 Nígbànáà ni àwọn ọkùnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ. wọ́n gbe ọkùnrin arọ kan; ènìyàn mẹ́rin ni ó gbé e. \v 4 Nígbàtí wọ́n kò sì le dé ọ̀dọ̀ rẹ nítorí ọ̀pọ́ ènìyàn, wọ́n sí òrùlé ibi tí Jésù wa, lẹ́yìn èyí ni wọ́n rí ààyè, wọ́n sì sọ ibùsùn tí ọkùnrin tí arọ náà sùn sí.

View File

@ -1 +1 @@
\v 5 Ó rí ìgbàgbọ́ wọn, Jésù sì wí fún ọkùnrin tí ó rọ naáà pé, "Ọmọkùnrin, a fi gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́" \v 6 Àwọn akọ̀wẹ́ sì joko síbẹ̀, wọ́n sì nrò nínú ọkàn wọn \v 7 Bawo ni ọkùnrin yi ti nsọ̀rọ̀ bayi? O nsọ̀rọ̀ òdì! Tani ẹni náà tí ó le fi ẹ̀sẹ̀ jìn bíkòse Ọlọ́run nìkan?"
\v 5 Jésù rí ìgbàgbọ́ wọn, Ó sì wí fún ọkùnrin arọ náà pé, "Ọmọkùnrin, a fi gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́" \v 6 Àwọn akọ̀wẹ́ sì joko síbẹ̀, wọ́n sì nrò nínú ọkàn wọn \v 7 Bawo ni ọkùnrin yi ti nsọ̀rọ̀ bayi? O nsọ̀rọ̀ òdì! Tani ẹni náà tí ó le fi ẹ̀sẹ̀ jìn bíkòse Ọlọ́run nìkan?"

View File

@ -36,7 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-05",
"02-08",
"02-10",
"02-13",