Thu May 16 2019 15:13:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 15:13:10 +01:00
parent 2bda905cb9
commit ddc1e5bd19
3 changed files with 2 additions and 4 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 2 \v 1 Nígbàtí Ó padà sí Kápánámù lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, ó di mímọ̀ wípé Ó wà nínú ilé. \v 2 Ọ̀pọ̀lọọpọ̀ sì péjọ níbẹ̀ tóbẹ̀ tí kò fi sí yè mọ́, kò sí lẹ́nu ìlẹ̀kùn pẹ̀lú, Jésù sì bá wọn sọ ọ̀rọ̀ náà.
\c 2 \v 1 Nígbàtí Ó padà sí Kápánámù lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, ó di mímọ̀ wípé Ó wà nínú ilé. \v 2 Ọ̀pọ̀lọọpọ̀ sì péjọ níbẹ̀ tóbẹ̀ tí kò fi sí ààyè mọ́, kò sí lẹ́nu ìlẹ̀kùn pẹ̀lú, Jésù sì bá wọn sọ ọ̀rọ̀ náà.

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Nígbànáà ni àwọn ọkùnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ. wọ́n gbe ọkùnrin tí ó rọ kan; mẹ́rin ló gbé e. \v 4 Nígbàtí wọ́n kò sì le dé ọ̀dọ̀ rẹ nítorí ọ̀pọ́ ènìyàn, wọ́n sí òrùlé ibi tí Jésù wa, lẹ́yìn èyí ni wọ́n rí aìyè, wọ́n sì sọ ibùsùn tí ọkùnrin tí ó rọ náà sùn sí.
\v 3 Nígbànáà ni àwọn ọkùnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ. wọ́n gbe ọkùnrin arọ kan; mẹ́rin ló gbé e. \v 4 Nígbàtí wọ́n kò sì le dé ọ̀dọ̀ rẹ nítorí ọ̀pọ́ ènìyàn, wọ́n sí òrùlé ibi tí Jésù wa, lẹ́yìn èyí ni wọ́n rí aìyè, wọ́n sì sọ ibùsùn tí ọkùnrin tí arọ náà sùn sí.

View File

@ -36,8 +36,6 @@
"AYANDEJI EMMANUEL"
],
"finished_chunks": [
"02-01",
"02-03",
"02-05",
"02-08",
"02-10",