diff --git a/02/23.txt b/02/23.txt index 8d861d5..e532a29 100644 --- a/02/23.txt +++ b/02/23.txt @@ -1 +1 @@ -\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kíló dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?" \ No newline at end of file +\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kí ni ó dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?" \ No newline at end of file diff --git a/02/25.txt b/02/25.txt index de2ceb7..fe50d55 100644 --- a/02/25.txt +++ b/02/25.txt @@ -1 +1 @@ -\v 25 Ó sì wí fun wọn pé, "Ẹ̀yin kò tí ka ohun tí Dáfídì se nígbàtí ó se aálaìní tí ebí sì npa á- oun pẹ̀lú àwọn okùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ- \v 26 bí ó ti wọ ilé Ọlọ́run nígbàtí Ábíátárì nse olú àlùfáà, ó sì jẹ àkàrà pẹpẹ, èyí tí kò bá òfin mu fún ẹnikẹ́ni láti jẹ ẹ̀ àfi àwọn àlùfáà, ó sì tún fi fún àwọn tí ó wà pẹ̀lú u rẹ̀.?" \ No newline at end of file +\v 25 Ó sì wí fun wọn pé, "Ẹ̀yin kò tí ka ohun tí Dáfídì se nígbàtí ó se aálaìní tí ebí sì npa á,- oun pẹ̀lú àwọn okùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ- \v 26 bí ó ti wọ ilé Ọlọ́run nígbàtí Ábíátárì nse olú àlùfáà, ó sì jẹ àkàrà pẹpẹ, èyí tí kò bá òfin mu fún ẹnikẹ́ni láti jẹ àfi àwọn àlùfáà, ó sì tún fi fún àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀.?" \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index e216119..b4904df 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -36,7 +36,6 @@ "AYANDEJI EMMANUEL" ], "finished_chunks": [ - "02-25", "02-27" ] } \ No newline at end of file