Tue Oct 22 2019 22:10:35 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-22 22:10:36 +01:00
parent af50e1a90b
commit 6c4cf3dbc9
4 changed files with 6 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 17 Ẹ má a ṣe àfarawé mi, ẹ̀yin ará. Ẹ má a ṣe àkíyèsí àwọn tí wọ́n ń rin déédé pẹ̀lú àpẹrẹ tí ẹ ní nínú wa. \v 18 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ńrìn -- àwọn tí mo ti máa ńsọ nípa wọn fún un yín, tí mo sì tún sọ fún un yín báyìí pẹ̀lú omijé -- bí àwọn ọ̀tá àgbélèbú Krístì. \v 19 Ìparun ni àtunbọ̀tán wọn. Nítorí ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń ṣògo nínú àwọn ohun ìtìjú wọn. Ohun ti ayé gba ọkàn wọn.
\v 17 Ẹ má a ṣe àfarawé mi, ẹ̀yin ará. Ẹ má a ṣe àkíyèsí àwọn tí wọ́n ń rin déédé pẹ̀lú àpẹrẹ tí ẹ ní nínú wa. \v 18 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ńrìn -- àwọn tí mo ti máa ńsọ nípa wọn fún un yín, tí mo sì tún sọ fún un yín báyìí pẹ̀lú omijé -- bí àwọn ọ̀tá àgbélèbú Krístì. \v 19 Ìparun ni àtunbọ̀tán wọn. Nítorí ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń ṣògo nínú àwọn ohun ìtìjú wọn. Ohun ayé ti gba ọkàn wọn.

View File

@ -1 +1 @@
\v 20 Ṣùgbọ́n ìlú ìbílẹ̀ wa ń bẹ ní ọ̀run, láti ibití àwa ti ń retí Olùgbàlà kan, Jésù Krístì Olúwa. \v 21 Yíò pa àwọn ara yẹpẹrẹ wa yí dà si èyí tí a dá ní ìrísí ara ògo tirẹ̀, èyí tí a dá nípa ipá Òun tìkara Rẹ̀ láti mú kí ohun gbogbo kí ó wà lábẹ́ ìsàkóso Rẹ̀.
\v 20 Ṣùgbọ́n ìlú ìbílẹ̀ wa ń bẹ ní ọ̀run, láti ibití àwa ti ń retí Olùgbàlà kan, Jésù Krístì Olúwa. \v 21 Yíò pa àwọn ara yẹpẹrẹ wa yí dà si èyí tí a dá ní ìrísí ara ògo tirẹ̀, èyí tí a dá nípa ipá agbára Òun tìkara Rẹ̀ láti mú kí ohun gbogbo kí ó wà lábẹ́ ìsàkóso Rẹ̀.

1
04/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹẹ̀rin

View File

@ -66,6 +66,8 @@
"03-06",
"03-08",
"03-12",
"03-15"
"03-15",
"03-17",
"03-20"
]
}