diff --git a/03/17.txt b/03/17.txt index f152b78..6e3fdfb 100644 --- a/03/17.txt +++ b/03/17.txt @@ -1 +1 @@ -\v 17 Ẹ má a ṣe àfarawé mi, ẹ̀yin ará. Ẹ má a ṣe àkíyèsí àwọn tí wọ́n ń rin déédé pẹ̀lú àpẹrẹ tí ẹ ní nínú wa. \v 18 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ńrìn -- àwọn tí mo ti máa ńsọ nípa wọn fún un yín, tí mo sì tún sọ fún un yín báyìí pẹ̀lú omijé -- bí àwọn ọ̀tá àgbélèbú Krístì. \v 19 Ìparun ni àtunbọ̀tán wọn. Nítorí ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń ṣògo nínú àwọn ohun ìtìjú wọn. Ohun ti ayé gba ọkàn wọn. \ No newline at end of file +\v 17 Ẹ má a ṣe àfarawé mi, ẹ̀yin ará. Ẹ má a ṣe àkíyèsí àwọn tí wọ́n ń rin déédé pẹ̀lú àpẹrẹ tí ẹ ní nínú wa. \v 18 Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ńrìn -- àwọn tí mo ti máa ńsọ nípa wọn fún un yín, tí mo sì tún sọ fún un yín báyìí pẹ̀lú omijé -- bí àwọn ọ̀tá àgbélèbú Krístì. \v 19 Ìparun ni àtunbọ̀tán wọn. Nítorí ikùn wọn ni ọlọ́run wọn, wọ́n sì ń ṣògo nínú àwọn ohun ìtìjú wọn. Ohun ayé ti gba ọkàn wọn. \ No newline at end of file diff --git a/03/20.txt b/03/20.txt index 78bfeb2..163840d 100644 --- a/03/20.txt +++ b/03/20.txt @@ -1 +1 @@ -\v 20 Ṣùgbọ́n ìlú ìbílẹ̀ wa ń bẹ ní ọ̀run, láti ibití àwa ti ń retí Olùgbàlà kan, Jésù Krístì Olúwa. \v 21 Yíò pa àwọn ara yẹpẹrẹ wa yí dà si èyí tí a dá ní ìrísí ara ògo tirẹ̀, èyí tí a dá nípa ipá Òun tìkara Rẹ̀ láti mú kí ohun gbogbo kí ó wà lábẹ́ ìsàkóso Rẹ̀. \ No newline at end of file +\v 20 Ṣùgbọ́n ìlú ìbílẹ̀ wa ń bẹ ní ọ̀run, láti ibití àwa ti ń retí Olùgbàlà kan, Jésù Krístì Olúwa. \v 21 Yíò pa àwọn ara yẹpẹrẹ wa yí dà si èyí tí a dá ní ìrísí ara ògo tirẹ̀, èyí tí a dá nípa ipá agbára Òun tìkara Rẹ̀ láti mú kí ohun gbogbo kí ó wà lábẹ́ ìsàkóso Rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/04/title.txt b/04/title.txt new file mode 100644 index 0000000..4f36092 --- /dev/null +++ b/04/title.txt @@ -0,0 +1 @@ +Orí Kẹẹ̀rin \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 1898e98..c6d3c0c 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -66,6 +66,8 @@ "03-06", "03-08", "03-12", - "03-15" + "03-15", + "03-17", + "03-20" ] } \ No newline at end of file