Wed Oct 23 2019 04:47:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
parent
ac1079c24c
commit
b97b0a9195
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 14 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹ ṣe dáadáa láti nawọ́ sí mi nínú ìṣòro mi. \v 15 Ẹ̀yin ará Fílípì mọ̀ pé, ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìhìnrere, nígbàtí mo kúrò ní Masidóníà, ìjọ kankan kó kún mi lọ́wọ́ níti fífúnni àti gbígbà bíkòṣe ẹ́yin níkan. \v 16 Kódà nígbàtí mo wà ní Tẹsalóníka, ẹ fi ìrànwọ́ ráńṣẹ́ láti mójúto àìní mi ju ẹ̀ẹ̀kan lọ. \v 17 Kìíṣepé mò ń wá ẹ̀bùn náà, ṣùgbọ́n mo
|
||||
\v 14 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹ ṣe dáadáa láti nawọ́ sí mi nínú ìṣòro mi. \v 15 Ẹ̀yin ará Fílípì mọ̀ pé, ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìhìnrere, nígbàtí mo kúrò ní Masidóníà, ìjọ kankan kó kún mi lọ́wọ́ níti fífúnni àti gbígbà bíkòṣe ẹ́yin níkan. \v 16 Kódà nígbàtí mo wà ní Tẹsalóníka, ẹ fi ìrànwọ́ ráńṣẹ́ láti mójúto àìní mi ju ẹ̀ẹ̀kan lọ. \v 17 Kìíṣepé mò ń wá ẹ̀bùn náà. Kàkà bẹ́ẹ̀, mò ń wá àlékún èso fún un yín.
|
Loading…
Reference in New Issue