Wed Oct 23 2019 04:45:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-10-23 04:45:13 +01:00
parent 0eea9ac83a
commit ac1079c24c
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹ ṣe dáadáa láti nawọ́ sí mi nínú ìṣòro mi. \v 15 Ẹ̀yin ará Fílípì mọ̀ pé, ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìhìnrere, nígbàtí mo kúrò ní Masidóníà, ìjọ kankan kó kún mi lọ́wọ́ níti fífúnni àti gbígbà bíkòṣe ẹ́yin níkan. \v 16 Kódà nígbàtí mo wà ní Tẹsalóníka, ẹ fi ìrànwọ́ ráńṣẹ́ sí mi ju ẹ̀ẹ̀kan lọ. \v 17
\v 14 Síbẹ̀síbẹ̀, ẹ ṣe dáadáa láti nawọ́ sí mi nínú ìṣòro mi. \v 15 Ẹ̀yin ará Fílípì mọ̀ pé, ní ìbẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀ ìhìnrere, nígbàtí mo kúrò ní Masidóníà, ìjọ kankan kó kún mi lọ́wọ́ níti fífúnni àti gbígbà bíkòṣe ẹ́yin níkan. \v 16 Kódà nígbàtí mo wà ní Tẹsalóníka, ẹ fi ìrànwọ́ ráńṣẹ́ láti mójúto àìní mi ju ẹ̀ẹ̀kan lọ. \v 17 Kìíṣepé mò ń wá ẹ̀bùn náà, ṣùgbọ́n mo