Fri May 17 2019 09:19:31 GMT-1200 (Dateline Standard Time)
This commit is contained in:
parent
9bf9ebc993
commit
e83cd0ca55
|
@ -1 +1 @@
|
|||
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ení tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, o' sì tún bẹ̀ wípé, Ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína o ba lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ eniyan si ba lọ ati pe wọn sumọ pẹkipẹki ni agbegbe naa.
|
||||
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ení tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, o' sì tún bẹ̀ wípé, Ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína o ba lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì ba lọ àti pé wọ́n súmọ́ pẹ́kipẹki ni agbegbe naa.
|
Loading…
Reference in New Issue