Fri May 17 2019 09:17:31 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-17 09:17:32 -12:00
parent 9b78b0693b
commit 9bf9ebc993
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ení tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, o' sì tún bẹ̀ wípé, Ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní alafia. \v 24 Nitorina o ba lo. ọpọlọpọ eniyan si ba lọ ati pe wọn sumọ pẹkipẹki ni agbegbe naa.
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ení tí orúkọ rẹ̀ njẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, o' sì tún bẹ̀ wípé, Ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína o ba lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ eniyan si ba lọ ati pe wọn sumọ pẹkipẹki ni agbegbe naa.