Thu May 16 2019 12:55:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:55:35 +01:00
parent 69aa185d8b
commit ce11493494
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 44 \v 42 Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ọmọ kékeré tí o gbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn fun kí á so ọọlọ nlá mọ́n-ọn lọ́rùn kí á sì sọọ́ sìnú òkun. \v 43 Bí ọwọ́ rẹ kan bá mún ọ kọsẹ̀, gée dànù. Ó sàn fún ọ láti wọ ìjọba ọ̀run bíi akéwọ́ jù kí o lọ sí ọ̀run àpáàdì pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì lọ, nínú iná àjóìkú.
\v 44 \v 42 Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ọmọ kékeré tí o gbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn fun kí á so ọọlọ nlá mọ́-ọn lọ́rùn kí á sì sọọ́ sìnú òkun. \v 43 Bí ọwọ́ rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀, gée dànù. Ó sàn fún ọ láti wọ ìjọba ọ̀run bíi akéwọ́ jù kí o lọ sí ọ̀run àpáàdì pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì lọ, nínú iná àjóòkú.

View File

@ -1 +1 @@
\v 45 Bí ẹsẹ̀ rẹ kan bá mún ọ kọsẹ̀ pẹ̀lú, gée sọnù. Nitorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run bíi akésẹ̀ jù fún ọ pẹ̀lú ẹsẹ̀ méjèèjì, kí á sì gbé ọ jù sínú iná ọ̀run àpáàdì lọ \v 46
\v 45 Bí ẹsẹ̀ rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀ pẹ̀lú, gée sọnù. Nitorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run bíi akésẹ̀ jù fún ọ pẹ̀lú ẹsẹ̀ méjèèjì, kí á sì gbé ọ jù sínú iná ọ̀run àpáàdì lọ \v 46

View File

@ -1 +1 @@
\v 47 Bí ojú rẹ kan bá mún ọ kọsẹ̀, yọọ́ dànù. Nítorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run pẹ̀lú ojú kan jù kí o ní ojú méjèèjì kí á sì gbe ọ sọ sínú iná ọ̀run àpáàdì, \v 48 níbití ìpáàrà won kììkú, bẹ́ẹ̀ni iná won kììkú.
\v 47 Bí ojú rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀, yọọ́ dànù. Nítorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run pẹ̀lú ojú kan jù kí o ní ojú méjèèjì kí á sì gbe ọ sọ sínú iná ọ̀run àpáàdì, \v 48 níbití ìpáàrà won kììkú, bẹ́ẹ̀ni iná won kììkú.