Thu May 16 2019 12:53:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:53:35 +01:00
parent 9fea6c3a55
commit 69aa185d8b
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 38 Johánù wí fún Un pé, "Àwá rí ẹnìkan tí ó n le àwọn ẹ̀mi àìmọ́ jáde ní orúkọ Rẹ̀, àwa si dáalẹ́kun, nítorí kò tọ̀wálẹ́yìn." \v 39 Ṣùgbọ́n Jésù wí fún pé, "ẹ máṣe dá wọn lẹ́kun nítorípé kò sí ẹnikẹ́ni tí yíò se isẹ́ agbára ní orúkọ mi tí o jẹ́ sọ ohun búburú nípa mi."
\v 38 Johánù wí fún Un pé, "Àwá rí ẹnìkan tí ó n le àwọn ẹ̀mi àìmọ́ jáde ní orúkọ Rẹ̀, àwa si dáalẹ́kun, nítorí kò tọ̀wálẹ́yìn." \v 39 Ṣùgbọ́n Jésù wí fún pé, "ẹ máṣe dá wọn lẹ́kun nítorípé kò sí ẹnikẹ́ni tí yíò ṣe iṣẹ́ agbára ní orúkọ mi tí o jẹ́ sọ ohun búburú nípa mi."

View File

@ -1 +1 @@
\v 40 Ẹnikẹ́ni tí kòba sèlòdì síwa, ó wà pẹ̀lú wa. \v 41 Ẹnikẹ́ni tí ó fi ife omi kékeré fún ni nítorí tí ó jẹ́ ti Kristi, lóòtítọ́ ni mo sọ fún yín, kì yó pàdánù èrè rẹ̀.
\v 40 Ẹnikẹ́ni tí kòba sè ìlòdì síwa, ó wà pẹ̀lú wa. \v 41 Ẹnikẹ́ni tí ó fi ife omi kékeré fún ni nítorí tí ó jẹ́ ti Kristi, lóòtítọ́ ni mo sọ fún yín, kì yó pàdánù èrè rẹ̀.

View File

@ -1 +1 @@
\v 44 \v 42 Ẹnikẹ́ni tí ó bá mún ọ̀kan nínú àwọn ọmọ kékeré tí o gbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn fun kí á so ọọlọ nlá mọ́n-ọn lọ́rùn kí á sì sọọ́ sìnú òkun. \v 43 Bí ọwọ́ rẹ kan bá mún ọ kọsẹ̀, gée dànù. Ó sàn fún ọ láti wọ ìjọba ọ̀run bíi akéwọ́ jù kí o lọ sí ọ̀run àpáàdì pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì lọ, nínú iná àjóìkú.\v 44
\v 44 \v 42 Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ọmọ kékeré tí o gbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn fun kí á so ọọlọ nlá mọ́n-ọn lọ́rùn kí á sì sọọ́ sìnú òkun. \v 43 Bí ọwọ́ rẹ kan bá mún ọ kọsẹ̀, gée dànù. Ó sàn fún ọ láti wọ ìjọba ọ̀run bíi akéwọ́ jù kí o lọ sí ọ̀run àpáàdì pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì lọ, nínú iná àjóìkú.