Mon Nov 25 2019 04:01:01 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-25 04:01:02 -08:00
parent 1cde31992d
commit b03fb20520
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 3 Nígbàtí Jésù wà ní Bẹ́tánì ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀, bí ó ti jókǒ ní tábílì, obìnrin kan tí ó ní ìgò alabástà òróró iyebíye, tí ó jẹ́ aláìlábáwọn nérdì. Ó fọ́ ìgò náà ó sì dàá si ní orí. \v 4 Ṣùgbọ́n àwọn kan ń bínú. Wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ láàrín ara wọn, wọn sì wípé, "Kí ni ìdí tí a se fi òróró yi sòfò? \v 5 A kò bá ti ta òróró ìkunra dídùn yí ní ọ̀dúńrún dénárì, kí á sí fún àwọn aláìní." Wọ́n sí bá obìnrin nà wí.
\v 3 Nígbàtí Jésù wà ní Bẹ́tánì ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀, bí ó ti jókǒ ní tábílì, obìnrin kan tí ó ní ìgò alabástà òróró iyebíye, tí ó jẹ́ aláìlábáwọn nérdì. Ó fọ́ ìgò náà ó sì dàá si ní orí. \v 4 Ṣùgbọ́n àwọn kan ń bínú. Wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ láàrín ara wọn, wọn sì wípé, "Kí ni ìdí tí a se fi òróró yi sòfò? \v 5 A kò bá ti ta òróró ìkunra dídùn yí ní ọ̀dúńrún dénárì, kí á sí fún àwọn aláìní." Wọ́n sí bá obìnrin náà wí.

View File

@ -1 +1 @@
\v 6 Ṣùgbọ́n Jesu wípé, "Ẹ jọ̀wọ́ rẹ̀. ẽṣe tí ẹ̀yin fi ń ba a wí? ó ti se ohun dídára fún mi. \v 7 Nígbàgbogbo ní ẹ̀yin ní tálákà pẹ̀lú yín, ẹ̀yin sì le se oore fún wọn nígbà tí ó bá wù yín, ṣùgbọ́n èmi li ẹ̀yin kó ní nígbàgbogbo. \v 8 Ó ti ṣe èyí tí ó le ṣe: ó ti fi òróró kùn ara mi fún ìsìnkú mi. \v 9 Lótǐtó ni mo wí fun yín, níbikíbi tí a ó gbé wàásù ìhìnrere ní gbogbo aiyé, a ó sì sọ̀rọ̀ ohun tí obìnrín yǐ ṣe ní ìrántí rẹ̀.
\v 6 Ṣùgbọ́n Jesu wípé, "Ẹ jọ̀wọ́ rẹ̀. Kílódé tí ẹ̀yin fi ń ba a wí? Ó ti se ohun dídára fún mi. \v 7 Nígbà gbogbo ní ẹ̀yin ní tálákà pẹ̀lú yín, ẹ̀yin sì le se oore fún wọn nígbà tí ó bá wù yín, ṣùgbọ́n èmi li ẹ̀yin kó ní nígbàgbogbo. \v 8 Ó ti ṣe èyí tí ó le ṣe: ó ti fi òróró kùn ara mi fún ìsìnkú mi. \v 9 Lótǐtó ni mo wí fun yín, níbikíbi tí a ó gbé wàásù ìhìnrere ní gbogbo aiyé, a ó sì sọ̀rọ̀ ohun tí obìnrín yǐ ṣe ní ìrántí rẹ̀.

View File

@ -40,7 +40,7 @@
"finished_chunks": [
"14-title",
"14-01",
"14-06",
"14-03",
"14-12",
"14-15",
"14-17",