diff --git a/14/03.txt b/14/03.txt index 7be06e6..bd56df5 100644 --- a/14/03.txt +++ b/14/03.txt @@ -1 +1 @@ -\v 3 Nígbàtí Jésù wà ní Bẹ́tánì ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀, bí ó ti jókǒ ní tábílì, obìnrin kan tí ó ní ìgò alabástà òróró iyebíye, tí ó jẹ́ aláìlábáwọn nérdì. Ó fọ́ ìgò náà ó sì dàá si ní orí. \v 4 Ṣùgbọ́n àwọn kan ń bínú. Wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ láàrín ara wọn, wọn sì wípé, "Kí ni ìdí tí a se fi òróró yi sòfò? \v 5 A kò bá ti ta òróró ìkunra dídùn yí ní ọ̀dúńrún dénárì, kí á sí fún àwọn aláìní." Wọ́n sí bá obìnrin nà wí. \ No newline at end of file +\v 3 Nígbàtí Jésù wà ní Bẹ́tánì ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀, bí ó ti jókǒ ní tábílì, obìnrin kan tí ó ní ìgò alabástà òróró iyebíye, tí ó jẹ́ aláìlábáwọn nérdì. Ó fọ́ ìgò náà ó sì dàá si ní orí. \v 4 Ṣùgbọ́n àwọn kan ń bínú. Wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ láàrín ara wọn, wọn sì wípé, "Kí ni ìdí tí a se fi òróró yi sòfò? \v 5 A kò bá ti ta òróró ìkunra dídùn yí ní ọ̀dúńrún dénárì, kí á sí fún àwọn aláìní." Wọ́n sí bá obìnrin náà wí. \ No newline at end of file diff --git a/14/06.txt b/14/06.txt index be25266..5bd5546 100644 --- a/14/06.txt +++ b/14/06.txt @@ -1 +1 @@ -\v 6 Ṣùgbọ́n Jesu wípé, "Ẹ jọ̀wọ́ rẹ̀. ẽṣe tí ẹ̀yin fi ń ba a wí? ó ti se ohun dídára fún mi. \v 7 Nígbàgbogbo ní ẹ̀yin ní tálákà pẹ̀lú yín, ẹ̀yin sì le se oore fún wọn nígbà tí ó bá wù yín, ṣùgbọ́n èmi li ẹ̀yin kó ní nígbàgbogbo. \v 8 Ó ti ṣe èyí tí ó le ṣe: ó ti fi òróró kùn ara mi fún ìsìnkú mi. \v 9 Lótǐtó ni mo wí fun yín, níbikíbi tí a ó gbé wàásù ìhìnrere ní gbogbo aiyé, a ó sì sọ̀rọ̀ ohun tí obìnrín yǐ ṣe ní ìrántí rẹ̀. \ No newline at end of file +\v 6 Ṣùgbọ́n Jesu wípé, "Ẹ jọ̀wọ́ rẹ̀. Kílódé tí ẹ̀yin fi ń ba a wí? Ó ti se ohun dídára fún mi. \v 7 Nígbà gbogbo ní ẹ̀yin ní tálákà pẹ̀lú yín, ẹ̀yin sì le se oore fún wọn nígbà tí ó bá wù yín, ṣùgbọ́n èmi li ẹ̀yin kó ní nígbàgbogbo. \v 8 Ó ti ṣe èyí tí ó le ṣe: ó ti fi òróró kùn ara mi fún ìsìnkú mi. \v 9 Lótǐtó ni mo wí fun yín, níbikíbi tí a ó gbé wàásù ìhìnrere ní gbogbo aiyé, a ó sì sọ̀rọ̀ ohun tí obìnrín yǐ ṣe ní ìrántí rẹ̀. \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index a33df7f..dd0e1a6 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -40,7 +40,7 @@ "finished_chunks": [ "14-title", "14-01", - "14-06", + "14-03", "14-12", "14-15", "14-17",