Thu May 20 2021 12:52:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 12:52:13 +01:00
parent f5cc41434c
commit a33ba40874
3 changed files with 6 additions and 4 deletions

View File

@ -1,3 +1 @@
\c 8 \v 1 Ní ọjọ́ wọǹnì, bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ti péjọ, kò sí oúnjẹ fún wọn mọ́ láti jẹ. Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé,
\v 2 “Àánú ọ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí ṣe mí, nítorí pé ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti wà pẹ̀lú ù mi kò sì sí ohun tí wọn yíò jẹ. \v 3 Bí mo bá rán wọn lọ sí ilé wọn láà jẹun, wọn le dákú lójú ọ̀nà. Àwọn mìíràn nínú wọn ti ọ̀nà jíjìn wá.” \v 4 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Níbo ni a ó ti rí àkàrà tí ó tó láti fi bọ́ wọn nínú aṣálẹ̀ yìí?”
\c 8 \v 1 Ní ọjọ́ wọǹnì, bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ti péjọ, kò sí oúnjẹ fún wọn mọ́ láti jẹ. Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé, \v 2 “Àánú ọ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí ṣe mí, nítorí pé ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti wà pẹ̀lú ù mi kò sì sí ohun tí wọn yíò jẹ. \v 3 Bí mo bá rán wọn lọ sí ilé wọn láà jẹun, wọn le dákú lójú ọ̀nà. Àwọn mìíràn nínú wọn ti ọ̀nà jíjìn wá.” \v 4 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Níbo ni a ó ti rí àkàrà tí ó tó láti fi bọ́ wọn nínú aṣálẹ̀ yìí?”

3
08/05.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,3 @@
\v 5 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “ìṣù àkàrà mélòó lẹ ní lọ́wọ́?”
Wọ́n fèsì pé, “ìṣù àkàrà méje.”
6Nítorí náà, ó pàṣẹ fún àwọn ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó sì mú odindi àkàrà méje náà, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́, ó pín wọn fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé ka iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀. \v 6 dd

View File

@ -73,6 +73,7 @@
"04-35",
"04-38",
"04-40",
"08-title"
"08-title",
"08-01"
]
}