From a33ba40874f3e7e6322fe8c92d65d6f7d7b851f2 Mon Sep 17 00:00:00 2001 From: aanuoluwapoadegoke Date: Thu, 20 May 2021 12:52:13 +0100 Subject: [PATCH] Thu May 20 2021 12:52:12 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time) --- 08/01.txt | 4 +--- 08/05.txt | 3 +++ manifest.json | 3 ++- 3 files changed, 6 insertions(+), 4 deletions(-) create mode 100644 08/05.txt diff --git a/08/01.txt b/08/01.txt index 8567c1b..19b5a27 100644 --- a/08/01.txt +++ b/08/01.txt @@ -1,3 +1 @@ -\c 8 \v 1 Ní ọjọ́ wọǹnì, bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ti péjọ, kò sí oúnjẹ fún wọn mọ́ láti jẹ. Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé, - -\v 2 “Àánú ọ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí ṣe mí, nítorí pé ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti wà pẹ̀lú ù mi kò sì sí ohun tí wọn yíò jẹ. \v 3 Bí mo bá rán wọn lọ sí ilé wọn láà jẹun, wọn le dákú lójú ọ̀nà. Àwọn mìíràn nínú wọn ti ọ̀nà jíjìn wá.” \v 4 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Níbo ni a ó ti rí àkàrà tí ó tó láti fi bọ́ wọn nínú aṣálẹ̀ yìí?” \ No newline at end of file +\c 8 \v 1 Ní ọjọ́ wọǹnì, bí ọ̀pọ̀ ènìyàn ti péjọ, kò sí oúnjẹ fún wọn mọ́ láti jẹ. Jesu pe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀, ó wí fún wọn pé, \v 2 “Àánú ọ̀pọ̀ ènìyàn wọ̀nyí ṣe mí, nítorí pé ó tó ọjọ́ mẹ́ta tí wọ́n ti wà pẹ̀lú ù mi kò sì sí ohun tí wọn yíò jẹ. \v 3 Bí mo bá rán wọn lọ sí ilé wọn láà jẹun, wọn le dákú lójú ọ̀nà. Àwọn mìíràn nínú wọn ti ọ̀nà jíjìn wá.” \v 4 Àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ dá a lóhùn pé, “Níbo ni a ó ti rí àkàrà tí ó tó láti fi bọ́ wọn nínú aṣálẹ̀ yìí?” \ No newline at end of file diff --git a/08/05.txt b/08/05.txt new file mode 100644 index 0000000..c9470ca --- /dev/null +++ b/08/05.txt @@ -0,0 +1,3 @@ +\v 5 Jesu béèrè lọ́wọ́ wọn pé, “ìṣù àkàrà mélòó lẹ ní lọ́wọ́?” +Wọ́n fèsì pé, “ìṣù àkàrà méje.” +6Nítorí náà, ó pàṣẹ fún àwọn ènìyàn náà láti jókòó lórí ilẹ̀. Ó sì mú odindi àkàrà méje náà, ó dúpẹ́ lọ́wọ́ Ọlọ́run, ó sì bù wọ́n sí wẹ́wẹ́, ó pín wọn fún àwọn ọmọ-ẹ̀yìn rẹ̀ láti gbé ka iwájú àwọn ènìyàn, wọ́n sì ṣe bẹ́ẹ̀. \v 6 dd \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 6847498..ff5224b 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -73,6 +73,7 @@ "04-35", "04-38", "04-40", - "08-title" + "08-title", + "08-01" ] } \ No newline at end of file