Tue May 18 2021 11:14:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:14:47 +01:00
parent 84d5c90fbe
commit 892249bec6
3 changed files with 4 additions and 3 deletions

View File

@ -1,2 +1 @@
\v 12 Ẹ̀mí Mímọ́ náà sì darí Rẹ̀ sí inù aginjù. \v 13 Ó sì wà ní aginjù fún ogójì ọjọ́. A sì ti ọwọ́ Satani dán an wò, ó sì wà pẹ̀lú àwọn ẹranko ìgbẹ́. Àwọn angẹli sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un.
Pípe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn àkọ́kọ́
\v 12 Ẹ̀mí Mímọ́ náà sì darí Rẹ̀ sí inù aginjù. \v 13 Ó sì wà ní aginjù fún ogójì ọjọ́, ti Satani ń dán an wò. Ó sì wà pẹ̀lú àwọn ẹranko ìgbẹ́, àwọn angẹli sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un.

1
01/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Nísinsìyí lẹ́yìn ìgbà tí ọba Herodu ti fi Johanu sínú ẹ̀wọ̀n tan, Jesu lọ sí Galili, ó ń wàásù ìhìnrere ti ìjọba Ọlọ́run. 15Ó sì kéde wí pé, “Àkókò náà dé wàyí, ìjọba Ọlọ́run kù sí dẹ̀dẹ̀. Ẹ yípadà kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ yín, kí ẹ sì gba ìhìnrere yìí gbọ́.” \v 15 dd

View File

@ -41,6 +41,7 @@
"01-01",
"01-04",
"01-07",
"01-09"
"01-09",
"01-12"
]
}