Tue May 18 2021 11:12:47 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-18 11:12:48 +01:00
parent 9ebaad886e
commit 84d5c90fbe
1 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1,2 @@
\v 12 \v 13 ff
\v 12 Ẹ̀mí Mímọ́ náà sì darí Rẹ̀ sí inù aginjù. \v 13 Ó sì wà ní aginjù fún ogójì ọjọ́. A sì ti ọwọ́ Satani dán an wò, ó sì wà pẹ̀lú àwọn ẹranko ìgbẹ́. Àwọn angẹli sì ń ṣe ìránṣẹ́ fún un.
Pípe àwọn ọmọ-ẹ̀yìn àkọ́kọ́