Thu May 16 2019 12:49:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:49:35 +01:00
parent fa01620816
commit 871639f6a8
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 33 Lẹ́yìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bá ara yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n ṣe àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn."
\v 33 Lẹ́yìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bá ara yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n ṣe àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ó sì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn."

View File

@ -1 +1 @@
\v 36 Ó mún ọmọ kékeré kan Ó sì fi sí ààrin wọn. Jésù gbé e lọ́wọ́ Rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, \v 37 "Ẹnikẹ́ni tí ó bá gba ọmọdé kékeré yìí ní orúko mi, ó gbàmí pẹ̀lú, bí ẹnikẹ́ni básì gbà mí, kò gba èmi nìkan, sùgbọ́n ó gba ẹni tí ó ránmi pẹ̀lú."
\v 36 Ó mú ọmọ kékeré kan Ó sì fi sí ààrin wọn. Jésù gbé e lọ́wọ́ Rẹ̀ ó sì wí fún wọn pé, \v 37 "Ẹnikẹ́ni tí ó bá gba ọmọdé kékeré yìí ní orúko mi, ó gbà mí pẹ̀lú, bí ẹnikẹ́ni básì gbà mí, kò gba Èmi nìkan, sùgbọ́n ó gba Ẹni tí ó rán mi pẹ̀lú."