Thu May 16 2019 12:47:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:47:35 +01:00
parent 3f5086512d
commit fa01620816
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 30 Wọ́n sì jáde lọ kúrò níbẹ̀, wọ́n gba agbègbè Gálílì lọ. Jésù kò fẹ́ kí ẹnìkankan kí ó mọ ibi tí àwọn wà, \v 31 nítorí tí Ó n kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀. Ó sọ fún wọn wípé, "A ó fi Ọmọ Ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́, wọn ó sì ṣe ikú pa Á. Lẹ́yìn ìgbà tí Ó bá kú tán, lẹ́yìn ọjọ́ kẹta yíò jí dìde , \v 32 Sùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí ó n sọ yìí kò yé wọn, ẹ̀rù si n bàwọ́n láti bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀.
\v 30 Wọ́n sì jáde lọ kúrò níbẹ̀, wọ́n gba agbègbè Gálílì lọ. Jésù kò fẹ́ kí ẹnìkankan kí ó mọ ibi tí àwọn wà, \v 31 nítorí tí Ó n kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀. Ó sọ fún wọn wípé, "A ó fi Ọmọ Ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́, wọn ó sì ṣe ikú pa Á. Lẹ́yìn ìgbà tí Ó bá kú tán, lẹ́yìn ọjọ́ kẹta yíò jí dìde , \v 32 Sùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí ó n sọ yìí kò yé wọn, ẹ̀rù si n bà wọ́n láti bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀.

View File

@ -1 +1 @@
\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn."
\v 33 Lẹ́yìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bá ara yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n e àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn."