Tue May 14 2019 10:04:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 10:04:22 +01:00
parent 57f29a1c7e
commit 7b2659ba09
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 9 \v 1 Ó sì sọ fu´n wọn pe´, "Lóòtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú yín ni ó dúro´ níhìnyí tí kìyíò rí ikú kí wọ́n tó rí ìjọba ọlọ́run tí yíò dèé pẹ̀lú agbára." \v 2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mún Pétérù àti Jákọ́bù òhun Jòháánù pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sórí òkè gíga, wọ́n dáwà níbẹ̀. A sì paá láradà níwájú wọn. \v 3 Asọ Jésù bẹ̀rẹ̀ síí tàn bí i mọ̀nàmọ́ná, ó funfun gbòò, ó funfun ju ohun ìfọṣọ kí ìbósọ nínú ayé.
\c 9 \v 1 Jésù sì sọ fún wọn pé, "Lóòtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú yín ni ó dúro´ níhìnyí tí kìyíò rí ikú kí wọ́n tó rí ìjọba ọlọ́run tí yíò dèé pẹ̀lú agbára." \v 2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mún Pétérù àti Jákọ́bù òhun Jòháánù pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sórí òkè gíga, wọ́n dáwà níbẹ̀. A sì paá láradà níwájú wọn. \v 3 Asọ Jésù bẹ̀rẹ̀ síí tàn bí i mọ̀nàmọ́ná, ó funfun gbòò, ó funfun ju ohun ìfọṣọ kí ìbósọ nínú ayé.

View File

@ -1 +1 @@
Orí Kẹẹ̀
Orí Kẹẹ̀sán