Tue May 14 2019 10:02:20 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 10:02:21 +01:00
parent 24215b17d7
commit 57f29a1c7e
2 changed files with 2 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mòósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì n bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ósì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, ẹjẹ́ kí á se ibùgbé mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù ba won gidigidi)
\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mòósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì n bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ósì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, ẹjẹ́ kí á se ibùgbé mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi)

1
09/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Orí Kẹẹ̀mí