Tue May 11 2021 15:45:57 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
commit
6ba9865c35
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\c 2 \v 1 Nígbàtí Ó padà sí Kápánámù lẹ́yìn ọjọ́ díẹ̀, ó di mímọ̀ wípé Ó wà nínú ilé. \v 2 Ọ̀pọ̀lọọpọ̀ sì péjọ níbẹ̀ tóbẹ̀ tí kò fi sí ààyè mọ́, kò sí lẹ́nu ìlẹ̀kùn pẹ̀lú, Jésù sì bá wọn sọ ọ̀rọ̀ náà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 3 Nígbànáà ni àwọn ọkùnrin kan wá sọ́dọ̀ rẹ. wọ́n gbe ọkùnrin arọ kan; ènìyàn mẹ́rin ni ó gbé e. \v 4 Nígbàtí wọ́n kò sì le dé ọ̀dọ̀ rẹ nítorí ọ̀pọ́ ènìyàn, wọ́n sí òrùlé ibi tí Jésù wa, lẹ́yìn èyí ni wọ́n rí ààyè, wọ́n sì sọ ibùsùn tí ọkùnrin tí arọ náà sùn sí.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 5 Jésù rí ìgbàgbọ́ wọn, Ó sì wí fún ọkùnrin arọ náà pé, "Ọmọkùnrin, a fi gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́" \v 6 Àwọn akọ̀wé sì joko síbẹ̀, wọ́n sì nrò nínú ọkàn wọn: \v 7 "Bawo ni ọkùnrin yi ti nsọ̀rọ̀ bayi? O nsọ̀rọ̀ òdì! Tani ẹni náà tí ó le fi ẹ̀sẹ̀ jìn bíkòse Ọlọ́run nìkan?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 8 Lójú ẹsẹ́ Jésù mọ ohun tí wọn nrò láàrin ara wọn nínú ọkàn rẹ. Ó wí fún wọn, "Kílódé tí ẹ̀yín fi nro èyí nínú ọkàn yin?" \v 9 Èwo ni ó rorùn jù láti wí fún ọkùnrin tí arọ náà, 'A dárí gbogbo ẹ̀sẹ̀ rẹ jìn ọ́' tàbí lati wípé 'Dìde, gbé ibùsùn rẹ kí o sì ma rìn?'
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 10 Ṣùgbọ́n kí ẹ̀yin kí ó le mọ̀ wípé Ọmọ ènìyàn ní àsẹ ní ayé lati dárí ẹ̀sẹ̀ jìn" Ó wí fún ẹnití ó rọ náà, \v 11 "mo wí fún ọ, dìde, gbé ení rẹ, kí o sì ma lọ sí ilé rẹ." \v 12 Ó dìde lójú ẹsẹ́, ó sì gbé ení rẹ, ó sì jáde kúrò ninú ilé náà lójú gbogbo ènìyàn, tóbẹ̀ tí ẹnu sì ya gbogbo wọn, tí wọ́n sì fi ògo fún Ọlọ́run, wọ́n sì wípé, "A kò rí irú èyí rí rárá."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 13 Ó sì tún jáde lẹ́ba omi adágún kan, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó sì kọ́ wọn. \v 14 Bí Ó sì ti nkọjá lọ, Ó rí Lefi ọmọ Álféusì ti o joko ni àgọ́ agbowó òde, Ó sì wí fún un pé, "Tọ̀ mí lẹ́yìn." Ó dìde, ó sì tọ lẹ́yìn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 15 Jésù si njẹun nínú ilé Lefi àti ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ, wọn ba a jẹun pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ, ọ̀pọ̀lọpọ̀ sí wà níbẹ̀, wọ́n si ntọ lẹ́yìn. \v 16 Nígbàtí àwọn akọ̀wé, ti wọn jẹ́ Farisí, rí tí Jésù njẹun pẹ̀lú àwọn ẹlẹ́sẹ̀ àti àwọn agbowó òde, wọ́n wí fún àwon ọmọ ẹ̀yìn rẹ pe, "Kíló sẹlẹ̀ tí O nfi bá àwọn agbowó òde àti àwọn ẹlẹ́sẹ̀ jẹun?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 17 Nígbàtí Jésù gbọ́ ọ̀rọ̀ yí Ó wí fún wọn pe, "Àwọn ènìyàn tí ara wọn ya kò wá onísègùn; àwọn tí ara wọn kò yá ni wọ́n nílò rẹ. Èmi kò wá lati pe àwọn olododo bíkòse àwọn ẹlẹ́sẹ̀."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 18 Ó sì se, àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí ngba àwẹ̀. Àwọn ènìyàn kan wá, wọ́n sì wí fún pe, "Kíló dé tí àwọn ọmọ ẹ̀yìn Jòhánù àti àwọn ti Farisí fi ngbawẹ, sùgbọ́n àwọn ọmọ ẹ̀yín rẹ ko gbàwẹ̀?" \v 19 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ó seése kí àwọn tì ó wá sí ibi ìgbéyàwó ma gbàwẹ̀ nígbàtí ọkọ ìyàwó sì wà pẹ̀lú wọn?" Níwọ̀n ìgbàtí wọn bá sì ní ọkọ ìyàwó larin wọn, kò seése fún wọn lati gbàwẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 20 Sùgbọ́n ọjọ́ nbọ nígbàtí a o mu ọkọ ìyàwó kúrò lọ́dọ̀ wọn, nígbàyí, wọn yio gbàwẹ̀. \v 21 Kòsí enìkan tí nran aṣọ titun mọ́ ẹwu tí ó ti gbó, bíbẹ́ẹ̀kọ́, aṣọ titun tí a rán yio ya kúrò lára ti àtijọ́, yio si ya ju ti tẹ́lẹ̀ lọ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 22 Kòsí ẹnìkan tí nfi wáìnì titun sínú awọ wáìnì àtijọ́, bíkòsebẹ wáìnì náà yio bẹ́ awọ ti wáìnì àti awọ wáìnì yio sì sègbé pọ̀. Dípòo bẹ́ẹ̀, fi wáìnì titun sínú awọ wáìnì titun."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 23 Ní ọjọ́ ìsinmi, Jésù nkọjá larin àwọn oko ọkà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ si nre orí ọkà. \v 24 Àwọn Farisí sì wí fún pe, "Kíyèsíi, kí ni ó dé tí wọn nfi se èyí tí kò bá òfin mu ní ọjọ́ ìsinmi?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 25 Ó sì wí fun wọn pé, "Ẹ̀yin kò tí ka ohun tí Dáfídì se nígbàtí ó se aálaìní tí ebí sì npa á,- oun pẹ̀lú àwọn okùnrin tí ó wà lọ́dọ̀ rẹ- \v 26 bí ó ti wọ ilé Ọlọ́run nígbàtí Ábíátárì nse olú àlùfáà, ó sì jẹ àkàrà pẹpẹ, èyí tí kò bá òfin mu fún ẹnikẹ́ni láti jẹ àfi àwọn àlùfáà, ó sì tún fi fún àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀.?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 27 Jésù wípé, "Ọjọ́ ìsinmi wà fún ènìyàn, kìí se ènìyàn fún ọjọ́ ìsinmi." \v 28 Nítorínáà, Ọmọ Ènìyàn ni Olúwa, àní ti ọjọ́ ìsinmi pẹ̀lu.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
ORÍ KEJÌ
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\c 3 \v 1 Lẹ́ẹ̀kan si Jésù rìn lọ sínú sínágọ́gù ọkùnrin kan sí wà níbẹ̀ tí apá rẹ rọ \v 2 Àwọn kan sí wà níbẹ̀ tí wọ́n ń wò pẹ̀lú ìfura bóyá yíò wo okùnrin náà sàn ní ọjọ́ ìsimi kí wọn kí ó le ka ẹ̀sùn sií lọrùn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 3 Jésù sọ fún ọkùnrin tí apá rẹ rọ naa, "Dìde kí o sì dúró ni àárín àwọn ènìyàn yí." \v 4 Lẹ́hìn náà, ó bi àwọn ènìyàn naa léèré pé: Ǹjẹ́ ó bà òfin mu láti ṣerere ní ọjọ́ ìsimi tàbí ṣe búburú; lati gba ẹ̀mí là tàbí láti pa? Sùgbọ́n wọ́n dákẹ lai sọ̀rọ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 5 Ó sí wò yí ká pẹ̀lú ìbínú, àti pé inú rẹ bàjẹ́ nítorí àyà líle wọn, ó sì wí fun okùnrin náà pé, "Na ọwọ́ rẹ jade." Ó sì na ọwọ́ rẹ jáde, ó sí bọ̀ sípò. \v 6 Àwọn Farisí sì jáde lojukan nàà wọn si bẹ̀rẹ̀ si gbìmọ̀ pọ̀ pẹ̀lú àwọn Olùtẹ̀lé Hẹ́ródù bí wọn ó se pa Jésù.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 7 Lẹ́yìn naa Jésù pẹ̀lú àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ sì lọ sí odò Gálílì, ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ènìyàn sí tèlé wọn lati Gálílì ati lati Judia. \v 8 Láti Jerusalemu ati lati ilẹ̀ àwọn ará Édómù ati lati ẹ̀yìn odò Jódánì wa àti àgbègbè àwọn ará Tireni oun Sidoni wa. Ńigbá tí wọ́n sí gbọ́ àwọn ohun àrà tí à ń ti ọ́wọ rẹ̀ se ọ̀pọ́ àwọn ènìyàn tọọ wa.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 9 Ó sì rán àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ pe kí wọn kí ó seètò ọkọ̀ ojú omi kékeré kan sílẹ̀ fun ohun nítor´ ọ̀pọ̀ ènìyàn, kí wọn kí ó ma bá tẹẹ́ pa. \v 10 Ńitorí tí o tí wo ọ̀pọ̀ ènìyàn sàn ẹnikọ̀ọ̀kan tí ó ní ìpónjú ń gbìyàjú lati fi ọwọ́ kan an bí o tì wù kí o rí.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 11 Ńigbà kuú gbà tí àwọn ẹ̀mì aìmọ́ bá ri, wọn a tẹríba níwájú rẹ pẹ̀lú ariwo, wọn a wípé, "Ìwọ ni Ọmọ Olórun." \v 12 Ó sì pa wọn lẹ́nu mọ́ pé kí wọn máá se fi òun hàn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 13 Ó sì gùn orí òkè lọ, ó sì pe àwọn tí ò wuú, wọ́n sí tọọ́ wá. \v 14 Ó yan àwon méjìlá (tí òhun tìkara rẹ̀ pè ní aposteli), kí wọn kí ó le wà pẹ́lu rẹ̀ ati kí òhun le rán wọn lọ lati polongo ìhìn naa \v 15 ati lati ni àse lati lé àwọn èmí èsù jáde. \v 16 Lẹ́yìn èyí ó yan àwọn méjìlá: Símónì, ẹni tí ó pè ní Pétérù;
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 17 Jákọ́bù ọmọ Zébédè ati Jòhánù arákùnrin Jákọ́bù, àwọn ẹni tí ó pè ní Bòánájì, èyí tí ó túmọ̀ sí, àwọn ọmọ àrá; \v 18 ati Áńdérù, Fílípì, Batolómíù, Mátíù, Tọ́másì, Jákọ́bù ọmọ Áfáúsì, Tádáúsì, Símónì alàjàgbara \v 19 ati Júdásì Ìskáriọ́tù, ẹni tí yoò fií hàn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 20 Lẹ́yí èyí o lọ́ sí ilé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sì kójọ lẹẹ̀kan si tó bẹ̀ tí wọn kòle ràyè fún oúnjẹ. \v 21 Nígbà tí àwọn ẹbí rẹ sì gbọ́ nípa ohun tió ń sẹlẹ̀, wọ́n jáde lati lọ mú nitórití wọ́n wípé "kò mọ ohún tió ń se." \v 22 Àwọn Akọ̀wé tí ó ti Jerusalemu wá wípé, "ẹ̀mí beélsébúbù ti gbé e wọ̀" àti wípé "nípa olórí àwọn ẹ̀mí òkùnkùn ni ó ń lé áwọn ẹ̀mí òkùnkùn jáde."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 23 Jésù sì pe àwon ọmọ ẹ̀yìn rẹ sí apá kan ó sì pa òwe kan fún wọn wípé, "bá wo ni sátánì se le maà lé sátánì jáde?" \v 24 tí ìjọba kan bá yapa sí ara rẹ̀, ìjoba naa kò le serere \v 25 tí ilé kan bá yapa sí ara rẹ̀ ilé naa kole dúró.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 26 Bí sàtánì bá dìde tako ara rẹ̀, a yapa àti pé òhun kí o lè dúró sùgbọ́n òpín dé ba. \v 27 sùgbọ́n kò sí ẹni tí o lé wọ ilé alágbára okùnrin lọ kí ó sì kó lí ẹrù lọ láì kọ́kọ́ de okùnrin alágbára naa, lẹ́yìn na a sì ko lí ẹrù lọ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 28 Lootọ ni mo wí fun yín, gbogbo ẹ̀sẹ̀ àwọn ọmọ ènìyàn li ó ní ìdáríjì ati àwọn ọ̀rọ̀ òdì tí wọ́n sọ jáde, \v 29 sùgbọ́n ẹnikẹ́ni tí o bá sọ̀rọ̀ òdì tako ẹ̀mí mímọ́ ki yíò ri ìdáríjì gba lailai sùgbọ́n ó jẹ̀bi ẹ̀sẹ̀ ayérayé \v 30 Jésù sọ ǹkan yí nítorípé wọ́n sọ pé "Ó ní ẹ̀mí aìmọ́"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 31 Léyìn èyí ìyá rẹ ati àwọn arákùnrin rẹ wa, wọ́n dúró lóde. Wón sì rańsẹ́ si pe ki o wa lẹ́sẹ̀kesè. \v 32 Ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn si jókòó yi ka, wọ́n sì sọ fun wípé, "Ìyá rẹ ati àwọn arákùnrin rẹ dúró li òde, wọ́n wá ọ́ kiri "
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 33 Ó sì dá wọn lóhùn wípé, "ta ni ìyáà mi ati àwon arákùnkun mi?" \v 34 ó sì wo àwon ènìyàn tí ó jòkoó yíi ká, ó sì wípé, "Wo ìyáà mi ati àwon arákùnrin mi" \v 35 ẹnikẹ́ni tí ó bá se ìfé Ọlọ́run òhun ni arákùnrin mi, arábìnrin mi ati ìyá mi.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
Máákù Orí Kẹta
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\c 5 \v 1 Wọ̀n wá sí apa´keji`òkun, sí agbègbè àwọn Kérásènè. \v 2 Nígbàtí Jésù sí jáde kúrò nínú ọkọ̀ ojú omi, lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀ ọkuǹrin kan sí tọ̀ wá láti inù isà-okú tí óní èmi'-àimọ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 3 Ọkùnrin náà ma ńgbé nínú isà-òkú . Kò sì si ẹni tí o le dìímú, koda pelu ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀. \v 4 Wón ti ma ń dé è lọ́pọ̀lọpọ̀ ìgbà pẹ̀lú ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ ní ọwọ́ àtì ẹsẹ̀. Ọkùnrin yìí má ń gé ṣẹ́kẹ́ṣẹkẹ̀ tọwọ̀ atì tẹsẹ̀ sí wẹ́wẹ́. kòsí sí ẹni tí agbára rẹ̀ káa.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 5 Ní gbogbo ọ̀sán àti òru ni isà-òkú àti ní àwọn orí-òkè, Ó ma ń pariwo jáde Ó si ma tún ya ara rẹ̀ lára pẹ̀lú àwon òkúta tí ó mú. \v 6 Nígbàtí ó rí Jésù láti jìnnàjìnnà, ó sáré si, o sì wólẹ̀ níwájú rẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 7 Ó pariwo jade lohùn rara, "Ki ni mo ni se pẹ̀lú rẹ, Jésù Ọmọ Ọlọ́run ọ̀gá ògo? Mo bẹ Ọ lórúkọ̀ Ọlọrun nìkan, máse fòró mi." \v 8 Nítorí ti O ti ń sọ fún "jáde kúrò lára ọkúnrin náà, ìwọ ẹ̀mi àìmọ́."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 9 Ó sì bi lere, "Kínni orúko re?" Ó da lóhùn wípé, "Orúko mi ni Lígíónì, nítorí wípé a pọ̀." \v 10 O bẹ̀, o sì tún bẹ ẹ, láti ma lé àwọn kúrò ní agbègbè náà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 11 Ó sì se, agbo àwọn ẹlẹ́dẹ̀ sì jẹun lórí òkè, \v 12 Wọ́n sì bẹ́ẹ̀, wípé, "Rán wa lọ sí inú agbo ẹlẹ́dẹ̀; kí a sì wọ inú wọn lọ." \v 13 Ó sì gbà wọ́n láyè; àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sì jáde, wọ́n sì wọnù àwọn agbo ẹlẹ́dẹ̀ lọ, wọ́n sì sáré sọ̀kalẹ̀ lọ sínú òkun, bí ẹgbẹ̀rún méjì ẹlẹ́dẹ̀ si parun sínú òkun.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 14 Àwọn tí ó fi oúnjẹ fún àwọn elẹ́dẹ̀ náà sí sálọ, wọ́n sí ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ lárin ìlú àti ní gbogbo agbègbè, àwọn ènìyàn sì jáde láti rí ohun tí ó sẹlẹ̀. \v 15 Àwon ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n sì rí ọkùnrin ẹlẹ́mìí àìmọ́ náà, èyí tí ó kún fún Lígíónì, ó jóko pẹ̀lú ẹ̀wù lọ́rùn àti ọpọlọ tó yè koro.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 16 Àwọn tí ó sì rí ohun tí ó sẹlẹ̀ sí ọkùnrin ẹlẹ́mì àìmọ́ náà ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ ní kíkún fún wọn, wọ́n sì ròyìn fún wọn nípa ohun tí ó sẹlẹ̀ sí àwon ẹlẹ́dẹ̀. \v 17 Nígbànà ní wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sì ní bẹ̀ pé kó fi agbègbè àwọn sílẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 18 Nígbàtí ó wọnú ọkọ̀ ojú omi lọ, ọkùnrin aláimọ́ náà bẹ̀ pé kí ohun le wà pẹ́lù rẹ. \v 19 Sùgbọ́n Jésù kò gbàá láyè, sùgbọ́n ó dá lóhùn wípé, "Lọ sí ilé rẹ àti ọ̀dọ̀ àwọn mọ̀lẹ́bí re, kí ó royin ohun tí Olúwa tí se fún ọ àti bí ó ti fi anu han si ọ. \v 20 Ó sì lọ, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí polongo àwọn ohun ń la tí Jésù tí se fún ni agbègbé Dẹ́kápólísì, ẹnu sí yà gbogbo ènìyàn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 21 Nígbàtí Jésù tí re kojá sí òdì kejì, nínú ọkọ̀ ojú omi, ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn yii ká, bí ó ti wà lẹgbẹ òkun. \v 22 Ọ̀kan nínú àwon olùdarí sínágọ́gú, ẹní tí orúkọ rẹ̀ ńjẹ́ Jáírù, ó wáà, nígbàtí ó sì ri, o wólẹ̀ níwájú rẹ̀. \v 23 Ó bẹ̀ ẹ́, ó sì tún bẹ̀ wípé, ọmọ mi obìnrin kékeré fẹ́rẹ̀ kú. Mo bẹ̀ Ọ́, wá dá ọwọ́ rẹ lee kí ó le padà bọ̀ sí pò kí o sì wà ní àláfíà. \v 24 Nítorína Ó bá lo. ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn sì ba lọ àti pé wọ́n súmọ́ Ó pẹ́kípẹ́kí ní agbègbè náà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 25 Obìnrin kan sí wá ní bẹ tí o ní isun ẹ̀jẹ̀ fún ọdún méjìlá. \v 26 Ó tí ní orísiríìsi ìlàkọjá pẹ̀lú àwon onísègùn àti pé ó ti ná ohun gbogbo tí óní, sùgbọ́n, kàkà kí o sàn se ló ń le koko si. \v 27 Nígbàtí o sì gbó ìròyìn nípa Jésù, ò sí tọ̀ wá larin àwon èrò, ò dúró lẹ́yìn rẹ̀, ó sì fi ọwọ́ kan etí asọ Rẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 28 Nítorí tí ó wípé, "tí mo bá le fọwọ́ kan etí asọ Rẹ̀, èmi yóò gba ìwòsàn. \v 29 "Nígbàtí o fọwọ́ kan, ìsun ẹ̀jẹ̀ náà dáwọ́ dúró, ó sì mọ̀ lára rẹ̀ wípé ìsun ẹ̀jẹ̀ náà tí dáwọ́ dúró, pé ohun ti rí ìwòsàn nínú gbogbo ìdàmù náà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 30 Jésù sì ní ìmọ̀lára lẹ́ṣẹ̀kẹṣẹ̀ wípé agbára ti jáde kúrò lára òhun. Ó wò yíká láàrín èrò wípé, "tani ó fọwọ́ kan asọ mi?". \v 31 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ wí fún pé, "O ri bi àwọn ènìyàn yìí tí yípo Rẹ, ó sì ni, "tani ó fọwọ́ kàn mí?" \v 32 Jésù wò yíká láti rí ẹni tó ṣe eléyìí.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 33 Obìnrin náà, nítorí ó mọ ohun tí ó sẹlẹ̀, ó si bẹ̀rù pẹ̀lú ìwárìrì. Ó wa, ó sì kùnlẹ́ níwáju Rẹ̀, ò sí sọ òtítọ́ fún ún. \v 34 Ò sí wí fun pè, "Obìnrin, ìgbàgbọ́ rẹ mú ọ láradá. Ma lọ lalafia ki o si gba ìwòsàn kúrò nínú àrùn rẹ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 35 Bí ó ti ń sọ̀rọ̀ lọ́wọ́, àwọn kan wá láti ọ̀dọ̀ olórí sínágọ́gú, wípé "Ọmọ rẹ obìnrin ti kú, kí ló dé tí ó ńyọ Olùkóni lẹ́nu?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 36 Nígbàtí ohun tí wọ́n sọ dé etí ìgbo Jésù, Ó sọ fún olórí sínágọ́gú pé "Má bẹ̀rú, ìwọ sá gbàgbó". \v 37 Kò si gba ẹnikẹ́ni laye láti tẹ̀le, àyàfi Pétérù, Jákọ́bù ati Jòhánù arákùnrin Jákọ́bù. \v 38 Wọ́n sì wá sí ilé olórí sínágọ́gú, Ó sì ri àwọn ènìyàn tí wọ́n pariwo; wọ́n sọkún, wọ́n sì ké rora sókè.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 39 Nígbàtí Ò sí wọ ilé náà, Ó wí fún wọ́n wípé, "Kí lódé tí ẹ ń banújẹ́ tí ẹ ṣì ńsọkún? Ọmọ náà kò kú, sùgbọ́n ó sùn." \v 40 Wọ́n sì fi rẹ́rin. Sùgbọ́n Ó ti gbogbo wọ́n si ta. Ó sì mu baba ọmọ náà, ìyá ọmọ náà àti àwọn tí ó wà pẹ̀lú rẹ̀, Ó sì wọ́lè sí ibi tí ọmọ náà wa.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 41 Ó sì mu ọwọ́ ọmọ náà Ó sì wí fún wípé, "Talitha Koum!" èyí tí ó túmọ̀ sí wípé, "ọmọbìnrin, mo wí fún ọ, dìdé." \v 42 Lójú kanáà, ọmọ náà didé, ó sì ń rìn (Ó jé ọmọ ọdún méjìlá nigbana). Lẹ́sẹ̀kánnà ẹnu yà wọ́n, ìbẹ̀rù bojo sì mú ọkàn wọn. \v 43 Ó sì pàsẹ fún wọn wípé, ẹnikẹ́ni kò gbọdọ̀ mọ̀ ní pa rẹ̀. Ó sì wí fún wọn wípé, kí wọn fun lóúnjẹ jẹ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
Ori Kàrún
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\c 7 \v 1 Àwọn Farisí àti àwọn akọ̀wé tí wọ́n wá láti Jèrúsálẹ́mù pagbo yí Jésù ká.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 2 Wọ́n ríi wípé àwọn kan nínú àwọn ọmọẹ̀yìn Rẹ̀ ń jẹhun pẹ̀lú ọwọ́ àìmọ́, eyí ni, láì fọwọ́ . \v 3 (Nítorípé àwọn Farisí àti gbogbo àwọn Júù kìí jẹhun láì jẹ́ pé wọ́n bá fọwọ́, nítorípé wọ́n fi ọwọ́ gidi mú àsá àwọn àgbààgbà. \v 4 Tí àwọn Farisí bá ti ọjà dé, wọn kìí jẹhun bíkòsepé wọ́n bá kọ́kọ́ wẹ ara wọn, bẹ́ẹ̀ni wọ́n sì di àwọn àsà míràn náà mú sinsin, bíi fífọ ife ìmumi, ìkòkò, ohun èlò idẹ, àti àwọn tábìlì tí wọ́n bá fi jẹhun.)
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 5 Àwọn Farisí àti àwọn Akọ̀wé bèèrè lọ́wọ́ ọ Jésù, wípé, "Kílódé tí àwọn ọmọẹ̀yìn Rẹ kìí rìn ní ìbámu pẹ̀lú àsà àwọn àgbààgbà, nítorí wọ́n jẹ oúnjẹ wọn láì fọwọ́."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 6 Ṣùgbọ́n Ó wí fún wọn pé, "Ìsáyà sọtẹ́lẹ̀ dáradára nípa ẹ̀yin àgàbàgebè. Ó kọọ́ pé, àwọn ènìyàn yíì ń fi ètè wọn bu ọlá fún mi, sùgbọ́n ọkàn wọn jìnnà sí ọ̀dọ̀ mi. \v 7 Ìjọ́sìn tí kò wúlò ni wọ́n ń fún mi, wọ́n ń kọ̀ni ní ìlànà ènìyàn bíi àgbékalẹ̀ ara wọn.'
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 8 Ẹ pa òfin Ọlọ́run tì, ẹ sì di àsà ènìyàn mún sinsin." \v 9 Ó sì tún wí fún wọn pé, "Ẹ rò pé ẹ ti se ohun tí ó dára tó lójú ara yín, tí ẹ kọ òfin Ọlọ́run kí ẹ le se àmúlò àsà àtọwọ́dọ́wọ́ tiyín!" \v 10 Sebí Mósè wípé, 'Bọ̀wọ̀ fún bàbá àti ìyá rẹ,' àti wípé, 'ẹnikẹ́ni tí ó bá sọ ọ̀rọ̀ bàbá tàbí ìyá rẹ̀ làì dára kíkú ni yíó kùú.'
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 13 \v 11 Ṣùgbọ́n ẹ̀yin wípé, 'Bí ènìyàn kan bá sọ fún bàbá tàbí ìya rẹ̀ pé, "Ìrànlọ́wọ́ yòówù tí ó yẹ tí o kò bá rí gbà lọ́wọ́ọ̀ mi Kóbánì ni,"' (èyí ni, "Mo ti fi fún Ọlọ́run")- \v 12 Ẹ kò wá jẹ́ kí ọmọ le se ǹkankan fún bàbá tàbí ìya rẹ̀ mọ́. v 13 Ẹ ń pa òfin Ọlọ́run rẹ́ nípa àsà àtọwọ́dọ́wọ́ tí ẹ gbé kalẹ̀. àti ọ̀pọ̀ àwọn nǹkan bíi irú ìwọ̀nyí ni ẹ se.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 14 Ó tún pe ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn, Ó sì wí fún wọn pé, "Gbogbo ẹ̀yin ènìyàn ẹ tẹ́tí gbọ́ mi, kí òye kí ó sì yé yín. \v 15 Kòsí ohunkóhun láti òde àgọ́ ara ènìyàn tí ó le sọ ènìyàn di aláìmó nígbàtí ó báwọ inú ènìyàn. Bíkòse ohun tí ó jáde wá láti inú ènìyàn sí ìta ní ọ̀rọ̀ tàbí ní ìse, ni ó ń sọ ènìyàn di aláìmọ́." \v 16 "Bí ẹnikẹ́ni bá ní etí láti fi gbọ́, jẹ́ kí ó gbó."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 17 Ní àkókò yìí, nígbàtí Jésù kúrò lọ́dọ́ àwọn ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn náà tí Ó sì wọ inú ilé, àwọn ọmọẹ̀yìn Rẹ̀ bií léèrè ìbéèrè lórí òwe náà. \v 18 Jésù dá wọn lóhùn wípé, "Ẹ̀yin kò tún tíì lóye èyí náà ni bíí? Sé ẹ kò tíì ri pé kòsí ohunkóhun láti òde àgọ́ ara ènìyàn tí ó le sọ ènìyàn di aláìmọ́ nígbàtí ó báwọ inú ènìyàn, \v 19 nítorípé kò le wọ inú ọkàn lọ, ṣùgbọ́n ó ń lọ sí inú ikùn ènìyàn tí yíó sì gba ibẹ̀ di ohun tí a ya ìgbẹ́ rẹ̀ sí ilé ìyàgbẹ́?" Jésù sọ gbogbo ohúnjẹ di mímọ́ pẹ̀lú gbólóhùn ọ̀rọ̀ yìí.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 20 Ó wípé, ọ̀rọ̀ àti ìse tí ó jáde wá láti inú ènìyàn sí òde ni ó ń sọ ènìyàn di aláaìmọ́. \v 21 Nítorípé nínú ènìyàn, láti inú ọkàn wá ni àwọn èrò burúkú ti ń jáde wá, ìsekúse, olè jíjà, ìpànìyàn, \v 22 panságà, ojúkòkúrò, ìkà, ẹlẹ̀tàn, ọlọgbọ́n lójú ara rẹ̀, ìlàra, abaníjẹ́, agbéraga, aláìnírònú. \v 23 Láti inú ọkàn ni gbogbo ibi wọ̀nyí ti máa ń jáde wá, àwọn ló sì ń so ènìyàn di aláìmọ́."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 24 Ó sì dìde kúrò níbẹ̀, Ó sì lọ sí agbègbè Tírè àti Sídónì. Ó wọ inú ilé kan, kò sì fẹ́ kí ẹnikẹ́ni mọ̀ pé Òun wà níbẹ̀, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé kò le sápamọ́n fún wọn. \v 25 Ṣùgbọ́n lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, obìnrin kan tí ọmọ rè ní ẹ̀mí àìmọ́, gbọ́ nípa rẹ̀, ó wá, ó sì kúnlẹ̀ sílẹ̀ ní ibi ẹsẹ̀ rẹ̀. \v 26 Ara Gíríkì ni obìnrin náà ń se, ọmọ bíbí Sirofẹ́níkà níí se. Ó bẹ Jésù kí ó bá òun lé ẹ̀mí èsù inú ọmọbìnrin òun jáde.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 27 Jésù wí fún un pé, "Jẹ́ kí àwọn ọmọ ilé Ísrẹ́lì kọ́kọ́ jẹhun ná, nítorípé kò dára kí á wá lọ gbé ohunjẹ àwọn ọmọ kí á lọ gbée fún àwọn kéfèrí." \v 28 Ṣùgbọ́n Obìnrin yìí dáhùn, ó wí fún Jésù pé, "Bẹ́ẹ̀ni, Olúwa, àwọn kèfèrí pàápàá le jẹ ẹ̀rúnrún ohúnjẹ àwọn ọmọ Ísrẹ́lì tí ó bá bọ́ sí ilẹ̀ láti oríi tábìlì."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 29 Ó wí fún un pé, "Nítorítí ìwọ́ sọ èyí, máa lọ lómìnira. Ẹ̀mí èsù náà ti jáde kúrò làra ọmọbìnrin rẹ." \v 30 Obìnrin náà sì padà lọ sí ilé rẹ̀, ó sì bá ọmọbìnrin rẹ̀ tí ó ń sùn lóríi bẹ́ẹ̀dì, àti wípé ẹ̀mí èsù náà ti fíi sílẹ̀ lọ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 31 Jésù tún kúrò ní agbègbè Tírè, Ó sì gba inú Sídónì lọ sí òkun Gálílì, ní ìgòkè lọ sí agbègbè Dẹ́kápólísì. \v 32 Àwọn ènìyàn gbé ẹnìkan tí kò gbọ́ ọ̀rọ̀, tí ó sì nira fún láti sọ̀rọ̀ wá sí ọ̀dọ̀ Jésù, wọ́n sì bẹ̀bẹ̀ wípé kí Jésù wòó sàn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 35 \v 34 Jésù mú ọkùnrin náà jáde sí ẹ̀gbẹ́ kan kúrò láàrin ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyan, Ó sì ń fi ìka rẹ̀ bọ ọkùnrin nàà létí, lẹ́yìn ìgbàtí Ó tutọ́ sí ọwọ́ Rẹ̀, Ó fi ọwọ́ kan ọkùnrin náà ní ahọ́n. \v 33 Jésù gbé ojú wo òkè ọ̀run, Ó mí kanlẹ̀, Ó wí fún ọkùnrin náà pé, "Éfátà" èyí tíí se "Ṣí!" Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ etí ìgbọ́ràn rè sì ṣí, Jésù sì tú ahọ́n rẹ̀ sílẹ̀ kúrò lọ́wọ́ àìlé sọ̀rọ̀, ó sì sọ̀rọ̀ yékéyéké.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 36 Jésù kìlọ̀ fún wọn pé kí wọ́n máse sọ fún ẹni kankan. Sùgbọ́n bí Ó ti ń kìlọ̀ fún wọn tó bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n sì ń polongo Rẹ̀ síi. \v 37 Ẹnu ya àwọn ènìyàn kọjá gidigidi, wọ́n sì ń wípé, "Ó ti se gbogbo ǹkan dáradára. Ó mú kí adití gbọ́ràn, Ó sì mú kí ẹnití kò le sọ̀rọ̀ di ẹnití ó ńsọ̀rọ̀."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
Orí Keèje
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\c 9 \v 1 Jésù sì wi fún wọn pé, "Lóòtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú yín tí ó dúró níhìńyí ní kì yíò rí ikú kí wọ́n tó rí ìjọba ọlọ́run tí yíò dè pẹ̀lú agbára." \v 2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mú Pétérù àti Jákọ́bù àtiJòhánù pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sórí òkè gíga, wọ́n dáwà níbẹ̀. A sì paá láradà níwájú wọn. \v 3 Aṣọ Rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ síí tàn bí i mọ̀nàmọ́ná, ó funfun bí ọṣẹ ìfọṣọ ayé kan ìbá fi fọ̀ ọ́ lọ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì ń bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ó sì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, Ẹ jẹ́ ká kọ́ ilé'gbe mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi)
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 7 Àwọ̀ sánmọ́ sì ṣíjibòwọ́n mọ́lẹ̀. Lẹ́sẹ̀kẹṣè, ohùn kan jáde wá láti inú àwọ̀ọsánmọ̀ wá wípé, "Èyí ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹ máa gbọ́ tirẹ̀." \v 8 Bí wọ́n ti wò àyíká wọn, wọn kò rí ẹnìkankan pẹ̀lú wọn mọ́, bíkòṣe Jésù nìkan.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 9 Bí wọ́n ti ń ti orí òkè sọ̀kalẹ̀, Jésù pàṣẹ fún wọn láti máṣe sọ ohun tí wọ́n ti rí fún ẹnikẹ́ni, títí tí àwọn ọmọ ènìyán yíò fi jí dìde láàrin àwọn òku. \v 10 Nítorínà, wọ́n pa ọ̀rọ̀ náà mọ́ láàrin ara wọn, ṣùgbọ́n wọ́n ń jíròrò láàrin ara wọn nípa ohun tí "jíjí dìde kúrò láàrin àwọn òku" túmọ̀ sí.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 11 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn bi Jésù léèrè pé, "Èéṣe tí àwọn akọ̀wé fi ṣọ wípé Èlíjà ni ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ wá."? \v 12 Jésù wí fún wọn pé, "Èlíjà ti kọ́kọ́ wá ná láti mún ohungbogbo padàbòsípò.Èéṣe tí a wá fi kọ̀wé rẹ̀ pé Ọmọ ènìyàn gbọ́dọ́ jìyà ohun púpọ̀ kí á sì se Ṣé bíi ẹni tí kòní láárii? \v 13 Ṣùgbọ́n èmi wí fún n yín pé Èlíjá ti wá ná, wọ́n sì seé ohun gbogbo tí ó wù wọ́n síi, gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ ti wí nípa rẹ̀."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 14 Nígbàtí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn yókù, wọ́n sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò yí wọn ká bẹ́ẹ̀ni àwọn akọ̀wé sì ń bá wọn wíjọ́. \v 15 Bí wọ́n ti rí Jésù, ẹnu ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò náà bẹ́ẹ̀ni wọ́n sáré pàdé rẹ̀ wọ́n sì kíi. \v 16 Ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ wípé, "Kíni ẹ̀yin bá wọn se àríyànjiyàn síi?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 17 Ẹnìkan láàrín èrò sì dáhùn ó wípé, "Olùkó, mo mú ọmọ mi tọ̀ Ọ́ wá.Ẹ̀míkẹ́mìí kan ti jẹ́ kó ya odi \v 18 Ó má ń gbáa mú, á sì gbée sánlẹ̀, bẹ́ẹ̀ni ó má ń mú kí ó máa pòfóló, kí ó sì ma payín keke, òun á sì gan pa. Mo bẹ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ kí wọ́n leèle jáde kúrò nínú rẹ̀ sùgbọ́n wọn kò leè ṣeé." \v 19 Ó sì wí fun wọn pé, "Ìran aláìgbàgbọ́, èmi ó ti bá n yín gbé pẹ́ tó? Èmi ó ti mú sùúrù pẹ́ tó fún n yín? Mú u wá fún mi.?"
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 20 Wọ́n mú ọmọkùnrin náà wá sọ́dọ̀ rẹ̀, nígbàtí ẹ̀mí náà rí Jésù, ó jẹ́ kí gììrì ki ọmọ náà lójijì. Ọmọkùnrin náà ṣubú lulẹ̀ ó sì ń pòfóló. \v 21 Jésù bá bi bàbá ọmọ náà, "Ó ti pẹ́ tó tí ti wà nírú ipò yìí?" Bàbá rẹ̀ dáhùn ówípé, "Láti ìgbà èwe rẹ̀ ni. Ní ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìgbà, \v 22 ó tilẹ̀ má n gbe jù sínú iná tàbí sínú omi láti paá lára nígbà míràn. Bí O bá le se ohun kóhun, sàánú fún wa kí o sì ràn wá lọ́wọ́."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 23 Jésù wí fún pé, "Bí ìwọ bá nípá? Ohun gbogbo ni ṣíṣe fún àwọn tí ó gbàgbọ́." \v 24 Lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀, bàbá ọmọ náà kígbe sókè wípé, "Mo gbàgbọ́! Ran àìgbàgbọ́ mi lọ́wọ´." \v 25 Nígbàtí Jésù rí ọ̀pọ̀ èrò tó n wá sọ́dọ̀ rẹ̀, Ó bá ẹ̀mí àìmọ́ náà wí, ó wípé, "Ìwọ ẹ̀mí odi àti ìdití, mo pàṣẹ fún ọ, jáde kúrò lára rẹ̀ kí o má sì ṣe padà síbẹ̀ mọ́."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 26 kígbe tòò ó sì jẹ́ kí gììrì ki ọmọ náà gidigidi, ó sì jáde kúrò lára rẹ̀. Ọmọkùnrin náà sì ń wò bíi ẹnití ó ti kú, tóbẹ̀ẹ̀ tí àwọn ènìyàn fi wí pé, "ó ti kú". \v 27 Sùgbọ́n Jésù gbá ọwọ́ ọmọ náà mú, Ó fàá sókè, ọmọ náà sì dìde dúró.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 28 Nígbàtí Jésù sì wọlé wá, àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ bií ní ìkọ̀kọ̀ pé, "Èéṣe tí àwa kò fi le è lèe jáde." \v 29 Ó dáhùn ósì wí fún won pé, "Irú èyí kò le ṣééṣe bíkòṣe nípasẹ̀ àdúrá."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 30 Wọ́n sì jáde lọ kúrò níbẹ̀, wọ́n gba agbègbè Gálílì lọ. Jésù kò fẹ́ kí ẹnìkankan kí ó mọ ibi tí àwọn wà, \v 31 nítorí tí Ó n kọ́ àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀. Ó sọ fún wọn wípé, "A ó fi Ọmọ Ènìyàn lé àwọn ènìyàn lọ́wọ́, wọn ó sì ṣe ikú pa Á. Lẹ́yìn ìgbà tí Ó bá kú tán, lẹ́yìn ọjọ́ kẹta yíò jí dìde , \v 32 Sùgbọ́n ọ̀rọ̀ tí ó n sọ yìí kò yé wọn, ẹ̀rù si n bà wọ́n láti bèèrè lọ́wọ́ Rẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 33 Lẹ́yìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bá ara yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n ṣe àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ó sì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 36 Ó mú ọmọ kékeré kan Ó sì fi sí ààrin wọn. Jésù gbé e lọ́wọ́ Rẹ̀ ó sì wí fún wọn pé, \v 37 "Ẹnikẹ́ni tí ó bá gba ọmọdé kékeré yìí ní orúko mi, ó gbà mí pẹ̀lú, bí ẹnikẹ́ni básì gbà mí, kò gba Èmi nìkan, sùgbọ́n ó gba Ẹni tí ó rán mi pẹ̀lú."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 38 Johánù wí fún Un pé, "Àwá rí ẹnìkan tí ó n le àwọn ẹ̀mi àìmọ́ jáde ní orúkọ Rẹ̀, àwa si dáalẹ́kun, nítorí kò tọ̀wálẹ́yìn." \v 39 Ṣùgbọ́n Jésù wí fún pé, "ẹ máṣe dá wọn lẹ́kun nítorípé kò sí ẹnikẹ́ni tí yíò ṣe iṣẹ́ agbára ní orúkọ mi tí o jẹ́ sọ ohun búburú nípa mi."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 40 Ẹnikẹ́ni tí kòba sè ìlòdì síwa, ó wà pẹ̀lú wa. \v 41 Ẹnikẹ́ni tí ó fi ife omi kékeré fún ni nítorí tí ó jẹ́ ti Kristi, lóòtítọ́ ni mo sọ fún yín, kì yó pàdánù èrè rẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 44 \v 42 Ẹnikẹ́ni tí ó bá mú ọ̀kan nínú àwọn ọmọ kékeré tí o gbàgbọ́ nínú mi kọsẹ̀, ó sàn fun kí á so ọọlọ nlá mọ́-ọn lọ́rùn kí á sì sọọ́ sìnú òkun. \v 43 Bí ọwọ́ rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀, gée dànù. Ó sàn fún ọ láti wọ ìjọba ọ̀run bíi akéwọ́ jù kí o lọ sí ọ̀run àpáàdì pẹ̀lú ọwọ́ méjèèjì lọ, nínú iná àjóòkú.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 45 Bí ẹsẹ̀ rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀ pẹ̀lú, gée sọnù. Nitorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run bíi akésẹ̀ jù fún ọ pẹ̀lú ẹsẹ̀ méjèèjì, kí á sì gbé ọ jù sínú iná ọ̀run àpáàdì lọ \v 46
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 47 Bí ojú rẹ kan bá mú ọ kọsẹ̀, yọọ́ dànù. Nítorí ó sàn fún ọ láti wọ Ìjọba ọ̀run pẹ̀lú ojú kan jù kí o ní ojú méjèèjì kí á sì gbe ọ sọ sínú iná ọ̀run àpáàdì, \v 48 níbití ìpáàrà wọn kììkú, bẹ́ẹ̀ni iná wọn kììkú.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 49 Nítorí olúkúlùkù ni a o fi iyọ̀ mú dùn pẹ̀lú iná. \v 50 Iyọ̀ dára, ṣùgbọ́n bí iyọ̀ bá sọ adùn rẹ̀ nù, báwo ni a o ṣe mú dùn padà? Ẹní iyọ̀ láàrin ara yín, ki ẹ sì wà ní àlàáfsíà pẹ̀lú ara yín."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
Orí Kẹẹ̀sán
|
|
@ -38,7 +38,12 @@
|
|||
"Oluwafemi Amoran",
|
||||
"Tobyno88",
|
||||
"adegokeaanuoluwapo",
|
||||
"abidoyewuraola"
|
||||
"abidoyewuraola",
|
||||
"AYANDEJI EMMANUEL",
|
||||
"ALAMU, ESTHER OYELOLA",
|
||||
"Matthew Oladipupo Aremu",
|
||||
"Sijuade Caleb Okunade",
|
||||
"OYEKOLA VICTOR OYEYEMI"
|
||||
],
|
||||
"finished_chunks": [
|
||||
"10-title",
|
||||
|
@ -116,6 +121,68 @@
|
|||
"14-57",
|
||||
"14-60",
|
||||
"14-69",
|
||||
"14-71"
|
||||
"14-71",
|
||||
"02-01",
|
||||
"02-03",
|
||||
"02-05",
|
||||
"02-08",
|
||||
"02-10",
|
||||
"02-13",
|
||||
"02-15",
|
||||
"02-17",
|
||||
"02-18",
|
||||
"02-20",
|
||||
"02-22",
|
||||
"02-23",
|
||||
"02-25",
|
||||
"02-27",
|
||||
"07-01",
|
||||
"07-02",
|
||||
"07-05",
|
||||
"07-06",
|
||||
"07-08",
|
||||
"07-11",
|
||||
"07-14",
|
||||
"07-17",
|
||||
"07-20",
|
||||
"07-24",
|
||||
"07-27",
|
||||
"07-29",
|
||||
"07-31",
|
||||
"07-33",
|
||||
"07-36",
|
||||
"03-title",
|
||||
"03-01",
|
||||
"03-03",
|
||||
"03-05",
|
||||
"03-07",
|
||||
"03-09",
|
||||
"03-11",
|
||||
"03-13",
|
||||
"03-17",
|
||||
"03-20",
|
||||
"03-23",
|
||||
"03-26",
|
||||
"03-28",
|
||||
"03-31",
|
||||
"03-33",
|
||||
"05-title",
|
||||
"05-01",
|
||||
"05-03",
|
||||
"05-05",
|
||||
"05-07",
|
||||
"05-09",
|
||||
"05-11",
|
||||
"05-14",
|
||||
"05-18",
|
||||
"05-21",
|
||||
"05-25",
|
||||
"05-28",
|
||||
"05-30",
|
||||
"05-33",
|
||||
"05-35",
|
||||
"05-36",
|
||||
"05-39",
|
||||
"05-41"
|
||||
]
|
||||
}
|
Loading…
Reference in New Issue