Tue May 11 2021 15:45:39 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)
This commit is contained in:
commit
c7c76990f8
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\c 14 \v 1 Ó ku ọjọ́ méjì sí àjọ ìrékọjá àti àjọ àíwúkárà. Àwọn olórí àlúfà àti akọ̀wé ń ro bí wọn yí ò ti rora mú Jésù láì fura kí wọn sí pá. \v 2 Nítorí wón ń sọ wípé, "Kìí se nígbà ọdún, kí rúkèrúdò má baà sẹlẹ̀ láàrín àwọn ènìyàn.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 3 Nígbàtí Jésù wà ní Bẹ́tánì ní ilé Símónì adẹ́tẹ̀, bí ó ti jókǒ ní tábílì, obìnrin kan tí ó ní ìgò alabástà òróró iyebíye, tí ó jẹ́ aláìlábáwọn nérdì. Ó fọ́ ìgò náà ó sì dàá si ní orí. \v 4 Ṣùgbọ́n àwọn kan ń bínú. Wọ́n sì ń sọ̀rọ̀ láàrín ara wọn, wọn sì wípé, "Kí ni ìdí tí a se fi òróró yi sòfò? \v 5 A kò bá ti ta òróró ìkunra dídùn yí ní ọ̀dúńrún dénárì, kí á sí fún àwọn aláìní." Wọ́n sí bá obìnrin náà wí.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 6 Ṣùgbọ́n Jesu wípé, "Ẹ jọ̀wọ́ rẹ̀. Kílódé tí ẹ̀yin fi ń ba a wí? Ó ti se ohun dídára fún mi. \v 7 Nígbà gbogbo ní ẹ̀yin ní tálákà pẹ̀lú yín, ẹ̀yin sì le se oore fún wọn nígbà tí ó bá wù yín, ṣùgbọ́n èmi ni ẹ̀yin kó ní nígbà gbogbo. \v 8 Ó ti ṣe èyí tí ó le ṣe: ó ti fi òróró kùn ara mi fún ìsìnkú mi. \v 9 Lótǐtó ni mo wí fun yín, níbikíbi tí a ó gbé wàásù ìhìnrere ní gbogbo aiyé, a ó sì sọ̀rọ̀ ohun tí obìnrín yǐ ṣe ní ìrántí rẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 10 Nígbànáà ni Júdásì Iskariotu, ọ̀kan nínú àwọn méjìlà, sì tọ̀ àwọn olóri àlúfà lọ láti fàá le wọn lọ́wọ́.
|
||||
\v 11 Nígbàtí àwọn olórí àlùfáà sì gbọ́ èyi, wọ́n yọ̀, wọ́n sì ṣe ìlérí láti fún n ní owó. Ó sì ń wá ọ̀nà láti fi lé wọn lọ́wọ́.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 12 Ní ọjọ́ kínǐ àjọ àìwúkárà, nígbàtí wọ́n pa ẹran ìrékọjà, àwọn ọmọ ẹ̀yìn wí fún n pé, "Níbo ni ìwọ fẹ́ kí á lọ pèsè sílẹ̀, kí ìwọ́ kí ó le jẹ ìrékọjá. \v 13 Ó sì rán méjì nínú àwọn ọmọ ẹ̀yin ó sì wí fún wọn pé, "E lọ sí iń ìlú, okùnrin tí ń ru 777 omi yíò pàde yín. Ẹ tẹ̀lẹ́ e. \v 14 NÍbití ó bá ti wọlé, ẹ tẹ̀lé e kí ẹ sì wí fún onílé wípé, 'Olùkọ́ni wípé, "NÍbo ni yàrá ìgbàlejò tí èmi yíò ti jẹ ìrékọjá pẹ̀lú àwọn ọmọ èyìn mi?"
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 15 Ò n ó sì fi gbọ̀ngàn ńlá kan tí a ti se lọ́sọ̌ lókè hàn yín tí a ti pèsè sílè. Níbẹ̀ ni kí ẹ̀yin kí ó pèsẹ̀ sílẹ̀ fún wa.
|
||||
\v 16 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì jáde lọ sí ìlú. Wọ́n sì rí i gẹ́gẹ́ bí ó ti sọ fún wọn, wọ́n sì pèsè ìrékọjá sílẹ̀.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 17 Nígbàtí alẹ́ lẹ́, ó wá pẹ̀lú àwọn méjìlá. \v 18 Bí wọ́n sì ti jókǒ tí wọ́n ń jẹun, Jésù wípé, "Lõtọ ni mo wí fún n yín, ọ̀kan nínú yín tí ó ń bá mi jẹun yíò fi mí hàn. \v 19 Wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí ní kãnú gidigidi, wọ́n sì ń bi ra wọn léérè lẽre lọ́kọ̃kan wípé, "Èmi ni bí?
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 20 Jésù sí dáhùn ó sì wí fún wọn pé, "Ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, tí ó ń tọwọ́ bọ̀ inú àwo pẹ̀lu mi.
|
||||
\v 21 Nítòótọ́ Ọmọ ènìyàn yíò lọ bí a ti kọ̀wé nípa tirẹ̀. Ṣùgbọ́n ègbé ni fún ọkùnrin nâ tí yíò jé sábàbí ìdàlè Ọmọ ènìyàn! ìbá sàn fún ọkùnrin náà tí a kò bá bí sáyé rárá.
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 22 Bí wọ́n sì ti ń jẹun, Jésù mú àkàrà, ó sì súre, ó sì pínn. Ó sì fifún wọn ó wípé, "Gba èyí. Èyí ni ara mi.
|
||||
\v 23 Ó sì gbé àgò, ó dúpẹ́, ó sì fifún wọn, gbogbo wọ́n sì mu nínú rẹ̀. \v 24 Ó wí fún wọn pé, "Èyí ni ẹ̀jẹ̀ mi ti májẹ̀mú, tí a ta sílẹ̀ fún ọ̀pọ èniyàn. \v 25 Lõtọ ni mo wí fu]n n yín, èmi kì yíò mu nínú èso àjàrà mọ́, títí yíò fi di ọjọ́ nà nígbàtí èmi ó muú ní titun ní ìjọba Ọlọ́run
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 26 Nígbàtí wọ́n ti kọ orin kan, wọ́n jáde lọ sí orí òkè Òlìfí. \v 27 Jésu wí fún wọn pé, " Gbogbo yín ni yíò kọsẹ̀, nítorítí a ti kọ̀wé rẹ̀ pé, 'Èmi ó lù olùṣọ́ àgùntàn agbo agùntàn yíò sì túká.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 28 Ṣùgbọ́n lẹ́yìn ìgbà tí mo bá jí dìde, èmi ó ṣájúu yín lọ sí Galili. \v 29 Peteru wí fún u pé, "Bí gbogbo ènìyàn tilẹ̀ kọsẹ̀, èmi kì yó kọsè."
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 30 Jésù wí fún u pé, "Lõtọ ni mo wí fún ọ, lásǎlẹ́ yi, kí àkùkọ kí ó tó kọ nígbà méjì, ìwọ ô kò mí nígba mẹ́ta.
|
||||
\v 31 Ṣùgbọ́n Pétérù wípé, "Bí ó bá jẹ́ ti ikú pẹ̀lú rẹ, èmi kò ní sẹ́ ọ." Gbogbo wọ́n sì jẹ́jẹ̌ kannáà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 32 Wón sì wá sí ibi kàn tí à ńpè ní Gẹ́tsímánì, ó sì wí fún àwọn ọmọ èyìn rẹ̀ pé, "Ẹ jókǒ ní ìhín nígbàtí mo bá lọ gbàdúrà. \v 33 Ó sì mú Pétérù àti Jákọ́bù àti Jòhánù pẹ̀lú rẹ̀, ó sì bẹ̀rẹ́ sí ní ìrẹ̀wẹ̀sí ọkàn, ọkàn rẹ̀ sì dàrú gidigidi. \v 34 Ó sì wí fún wọn pé, "Ọkàn mi ńkãnu gidigidi, títí dé ojú ikú. Ẹ dúró níhǐn kí ẹ sì mã ṣọ́nà.
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 35 Jésù sí lọ síwájú díẹ̀, ó sì dojúbolẹ̀, ó sì gbàdúrà pé, bí ó bá se é se, kí wákàtí yìí ré kọjá kúrò lórí rẹ̀.
|
||||
\v 36 Ó wípé, "Abba, Bàbá, ohun gbogbo ni síse fún ọ. Mú ago yìí kúrò lórí mi. ṣùgbọ́n kì íṣe ti ìfẹ́ mi, bíkòse ti ìwọ."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 37 Ó padà wá, ó sì rí wọn tí wón n sùn, ó sì wí fún Pétérù, "Símónì, ìwọ ń sùn bi? Ìwọ kò ha le sọ́nà fún wákàtí kan? \v 38 Ẹ máa sọ́nà kí e sì ma gbàdúrà kí ẹ̀yin kí ó má baà bọ́ sínú ìdánwò. Ẹ̀mí ń fẹ́ nítòótọ́, ṣùgbọ́n ó se àìlera fún ara." \v 39 Ó sì tún lọ kúrò ní ọ̀dọ̀ wọn láti lọ gbàdúrà, ó sì tún lo ọ̀rọ̀ kanńà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 40 Ó sì tún bá wọn tí wọn ń sùn, nítorí tí ojú wọn wúwo wọn kó sí mọ ohun tí wọn yí ò sọ fún n. \v 41 Ó sì wá ní ìgbà kẹta ó sì wí fún wọn pé, " Sé ẹ̀yin sí n sùn ni? Ó ti tó! Wákàtí náà ti dé. Wò ó! Ati fi ọmọ ènìyàn lé àwọn ẹlẹ́sẹ̀ lọ́wọ́. \v 42 Ẹ dìde; ẹ jẹ́kí á lọ. Wó ò, ẹni tí yíò dà mí ti wà nítòsí."
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Júdásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwé, àti àwọn àgbà. \v 44 Ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Ẹnikẹ́ni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Júdásì sì dé, lójúkanńà ó tọ Jésù wá ó sì wípé, "Olùkọ́," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára àwọn tí ó sún mọ́ wọn yọ idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlùfáà. \v 48 Jésù sì wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó fé mú olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbà gbogbo tí mo sì ń kọ́ọ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ sẹ." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jésù sì fií sílẹ̀ wọ́n sì sá lọ.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 51 Ọmọkùnrin kan, tí ó fi asọ ọ̀gbọ̀ nìkan wé ara rẹ̀, sì ń tẹ̀lẹ́ Jésù. Nígbà tí àwọn ọkùnrin náà sì mú Jésù. \v 52 Ó fi asọ ọ̀gbọ̀ náà sílẹ̀, ó sì sá kúrò ní ìhòhò.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 53 Wọ́n sì mú Jẹ́sù lọ ṣọ́dọ̀ olórí àlùfáà. Gbogbo àwọn olórí àlùfàà, àti àwọn àgbàgbà, àti àwọn akọ̀wé sì péjọ pẹ̀lú rẹ̀. \v 54 Pétérù sì n tọ̀ ọ́ lẹ́yìn ní òkèrè wọ̀ inú ilé, títí wọ́n fi dé àgbàlá olóri àlùfáà. Ó sì bá àwọn ẹ̀sọ́ jókǒ, tí wọ́n ń yáná.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 55 Nígbànáà ni àwọn olórí àlùfá àti gbogbo àjọ ìgbìmọ̀ júù ńwá ẹ̀rí lòdì sí Jésù láti pa á. Wọn kò sì rí ohun kan. \v 56 Nítorípé ọ̀pọ̀lọpọ̀ ni ó jẹ́rìí èké sí i, ṣùgbọ́n ohùn àwọn ẹlẹ́rǐ náà kò ṣọ̀kan.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 57 Àwọn kan sì dìde, wọ́n ń jẹ́rǐ èké sí i; wọ́n wípé, \v 58 "Àwa gbọ́ tí ó ún sọ wípé, Èmi ó wó tẹ́mpìlì yí tí a fi ọwọ́ ṣe, ní wọ̀n ijọ́ mẹ́ta èmi ó sì kọ́ òmíràn tì a kò fi ọwọ́ se." \v 59 Síbẹ̀ ẹ̀rí wọn kò sọ̀kan.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 60 Olórí àlùfáà sì dìde láarín wọn ó sì bi Jésù lêrè wípé, Ìwọ kò ní ìdáhùn bí, kíni ohun tí àwọn ènìyàn yín jẹ́rǐ lòdì sí ọ? \v 61 Ó sì dákẹ́, kò sì so ohunkóhun. Olórí àlùfáà sì bií lêrè wípé, "sé ìwọ ni Krístì ọmọ olùbùkún?" \v 62 Jésù wípé, "Èmi ni; ìwọ yíò sì rí ọmọ Ènìyàn nígbàtì ó bá jókǒ ní apá ọ̀tún agbára tí ó sì wà ní àwọ sánmọ̀."
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 63 Olórí àlùfáà sì fa asọ rẹ̀ ya ó sì wípe, "Sé a sì nílò ẹlẹ́rǐ bí? \v 64 Ẹ̀yín ti gbọ́ ọ̀rọ̀ ẹ̀gàn náà. Kíni ìpinu yín? Gbogbo wọn sì kẹ́gàn rẹ̀ gẹ́gẹ́ bíi ẹni tí ó yẹ fún ikú.
|
||||
\v 65 Àwọn míràn bẹ̀rẹ̀ sí ní tutọ́ síi lára wọ́n sì bo ojú rẹ̀ wọ́n sì lû wọ́n wí fun pé, "sọtẹ́lẹ̀!" Àwọn ọmọ ogun sì mú wọ́n sì lùú.
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 66 Bí Pétérù sì ti wà ní ìsàlẹ̀ ní àafin, ọ̀kan nínú àwọn ọmọbìnrin olórí àlùfáà wá sí ọ̀dọ̀ rẹ̀.
|
||||
\v 67 Ó rí Pétérù tí ó ńyáná, ó tẹjú mọ́ ọ, ó sì wípe, ìwọ́ wà pẹ̀lú Jésù aráa Násárẹ́tì yí. \v 68 Ṣùgbọ́n ó sẹ́ ẹ, ó wípé, "Èmi kò mó bẹ́ẹ̀ni òye ohun tí ìwọ ńsọ kò tilẹ̀ yé mi." Ó sì jáde lọ sí àgbàlá. Àkùkọ sì kọ.
|
|
@ -0,0 +1,2 @@
|
|||
\v 69 Ọmọbìnrin nǎ sì tún rí i, ó sì bẹ̀rẹ̀ sí ní sọ fún àwọn tí ó dúró níbẹ̀ pẹ́, "Ọ̀kan nínú wọn ni okùnrin yî.
|
||||
\v 70 Ó sì tún sẹ́ ẹ. Lẹ́yìn ìgbà díẹ̀, àwọn tí ó dúró níbẹ̀ tún wí fún Pétérù pé, "Lóòtọ́ ni, ọ̀kan nínú wọn ní ìwọ íṣe, nítorípé ará Gálílì ni ìwọ náà.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
\v 71 Ṣùgbọ́n ọ́ bẹ̀rẹ̀ sí ní fi ara rẹ̀ ré ó sì búra wípé, "Èmi kò mọ ọkùnrín yǐ tí ẹ̀ ń sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀." \v 72 Lójúkańnà àkùkọ sì kọ ní ìgbà kejì. Pétérù sí rántí ọ̀rọ̀ tí Jésù wí fún u pé: "Kí àkùkọ kí ó tó kọ lẹ́ẹ̀mejì , ìwọ ó sẹ́ mi lẹ́ẹ̀mẹta." ó bara jẹ́, ó sì sọkún.
|
|
@ -0,0 +1 @@
|
|||
Orí kẹrìnlá
|
|
@ -35,7 +35,10 @@
|
|||
"translators": [
|
||||
"Emmanuel A Adeniran",
|
||||
"Ajayi Julius Oluwafunminiyi",
|
||||
"Oluwafemi Amoran"
|
||||
"Oluwafemi Amoran",
|
||||
"Tobyno88",
|
||||
"adegokeaanuoluwapo",
|
||||
"abidoyewuraola"
|
||||
],
|
||||
"finished_chunks": [
|
||||
"10-title",
|
||||
|
@ -89,6 +92,30 @@
|
|||
"13-28",
|
||||
"13-30",
|
||||
"13-33",
|
||||
"13-35"
|
||||
"13-35",
|
||||
"14-title",
|
||||
"14-01",
|
||||
"14-03",
|
||||
"14-06",
|
||||
"14-10",
|
||||
"14-12",
|
||||
"14-15",
|
||||
"14-17",
|
||||
"14-20",
|
||||
"14-22",
|
||||
"14-26",
|
||||
"14-28",
|
||||
"14-30",
|
||||
"14-32",
|
||||
"14-35",
|
||||
"14-37",
|
||||
"14-40",
|
||||
"14-43",
|
||||
"14-47",
|
||||
"14-51",
|
||||
"14-57",
|
||||
"14-60",
|
||||
"14-69",
|
||||
"14-71"
|
||||
]
|
||||
}
|
Loading…
Reference in New Issue