Thu May 20 2021 14:42:13 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
aanuoluwapoadegoke 2021-05-20 14:42:13 +01:00
parent 8b7a99a820
commit 662ad90e2d
3 changed files with 8 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 13 NÍgbà náà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn. Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n fi èyí dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.”
\v 13 NÍgbà náà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” Kí àwa kí ó san án, tàbí kí a máa san án? \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn, Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.”

5
12/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1,5 @@
\v 16 Wọ́n mú owó idẹ náà fún , ó bi wọ́n léèrè pé, “Ẹ wò ó! Àwòrán àti orúkọ ta ni ó wà níbẹ̀?”
Wọ́n dáhùn pé, “Àwòrán àti orúkọ Kesari ni.”
17 Nígbà náà ni Jesu wí fún wọn pé, “Bí ó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ fi ohun tí ó bá jẹ́ ti Kesari fún Kesari. Ṣùgbọ́n ẹ fi ohun gbogbo tí í ṣe ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.”
Ẹnu sì yà wọ́n gidigidi sí èsì rẹ̀.
\v 17 ff

View File

@ -95,6 +95,7 @@
"12-04",
"12-06",
"12-08",
"12-10"
"12-10",
"12-13"
]
}