diff --git a/12/13.txt b/12/13.txt index 01eb4c5..42b0d4c 100644 --- a/12/13.txt +++ b/12/13.txt @@ -1 +1 @@ - \v 13 NÍgbà náà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn. Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n fi èyí dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.” \ No newline at end of file +\v 13 NÍgbà náà ni wọ́n rán àwọn Farisí pẹ̀lú àwọn kan tí í ṣe ọmọ-ẹ̀yìn Herodu wá sọ́dọ̀ Jesu, láti fi ọ̀rọ̀ rẹ̀ mú. \v 14 Bí wọn ti dé, wọ́n wí pé: “Olùkọ́, àwa mọ̀ pé ìwọ máa ń sọ òtítọ́ láìsí ìbẹ̀rù ẹnikẹ́ni. Òtítọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni ìwọ máa ń kọ́ni. Ńjẹ́ ó tọ́ tàbí kò tọ́ láti máa san owó orí fún Kesari?” Kí àwa kí ó san án, tàbí kí a máa san án? \v 15 Ṣùgbọ́n Jesu mọ ìwà àgàbàgebè wọn, Ó sì wí pé, “Èéṣe tí ẹ̀yin fi n dán mi wo? Ẹ mú owó idẹ kan wá kí n wò ó.” \ No newline at end of file diff --git a/12/16.txt b/12/16.txt new file mode 100644 index 0000000..edb9216 --- /dev/null +++ b/12/16.txt @@ -0,0 +1,5 @@ +\v 16 Wọ́n mú owó idẹ náà fún , ó bi wọ́n léèrè pé, “Ẹ wò ó! Àwòrán àti orúkọ ta ni ó wà níbẹ̀?” +Wọ́n dáhùn pé, “Àwòrán àti orúkọ Kesari ni.” +17 Nígbà náà ni Jesu wí fún wọn pé, “Bí ó bá rí bẹ́ẹ̀, ẹ fi ohun tí ó bá jẹ́ ti Kesari fún Kesari. Ṣùgbọ́n ẹ fi ohun gbogbo tí í ṣe ti Ọlọ́run fún Ọlọ́run.” +Ẹnu sì yà wọ́n gidigidi sí èsì rẹ̀. +\v 17 ff \ No newline at end of file diff --git a/manifest.json b/manifest.json index 8712c02..3463c24 100644 --- a/manifest.json +++ b/manifest.json @@ -95,6 +95,7 @@ "12-04", "12-06", "12-08", - "12-10" + "12-10", + "12-13" ] } \ No newline at end of file