Thu May 16 2019 12:13:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:13:35 +01:00
parent 29d9570d50
commit 4c79e5ab1e
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn bi Jésù léèrè pé, "Èéṣe tí àwọn akọ̀wé fi ṣọ wípé Èlíjà ni ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ wá."? \v 12 Jésù wí fún wọn pé, "Èlíjà ti kọ́kọ́ wá ná láti mún ohungbogbo padàbòsípò.Èése tí a wá fi kọ̀wé rẹ̀ pé Ọmọ ènìyàn gbọ́dọ́ jìyà ohunpúpọ̀ kí á sì seé bíi ẹni tí kòní láárii? \v 13 Sùgbọ́n èmi wí fún n yín pé Èlíjá ti wá ná, wọ́n sì seé ohungbogbo tí ó wù wọ́n síi, gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ ti wí nípa rẹ̀."
\v 11 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn bi Jésù léèrè pé, "Èéṣe tí àwọn akọ̀wé fi ṣọ wípé Èlíjà ni ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ wá."? \v 12 Jésù wí fún wọn pé, "Èlíjà ti kọ́kọ́ wá ná láti mún ohungbogbo padàbòsípò.Èéṣe tí a wá fi kọ̀wé rẹ̀ pé Ọmọ ènìyàn gbọ́dọ́ jìyà ohun púpọ̀ kí á sì se Ṣé bíi ẹni tí kòní láárii? \v 13 Ṣùgbọ́n èmi wí fún n yín pé Èlíjá ti wá ná, wọ́n sì seé ohun gbogbo tí ó wù wọ́n síi, gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ ti wí nípa rẹ̀."

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Nígbàtí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀hìn yókù, wọ́n sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò yí wọn ká bẹ́ẹ̀ni àwọn akọ̀wé sì ń báwọn wíjọ́. \v 15 Bí wọ́n ti rí Jésù, ẹnu ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò náà bẹ́ẹ̀ni wọ́n sáré pàdé rẹ̀ wọ́n sì kíi. \v 16 Ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ wípé, "Kíni ẹ̀yin bá wọn se àríyànjiyàn síi?"
\v 14 Nígbàtí wọ́n dé ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ-ẹ̀yìn yókù, wọ́n sì rí ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò yí wọn ká bẹ́ẹ̀ni àwọn akọ̀wé sì ń bá wọn wíjọ́. \v 15 Bí wọ́n ti rí Jésù, ẹnu ya ọ̀pọ̀lọpọ̀ èrò náà bẹ́ẹ̀ni wọ́n sáré pàdé rẹ̀ wọ́n sì kíi. \v 16 Ó bi àwọn ọmọ ẹ̀yìn Rẹ̀ wípé, "Kíni ẹ̀yin bá wọn se àríyànjiyàn síi?"