Thu May 16 2019 12:11:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:11:35 +01:00
parent 6ee7e846b3
commit 29d9570d50
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Bí wọ́n ti ń ti orí òkè sọ̀kalẹ̀, Jésù pàṣẹ fún wọn láti máṣe sọ ohun tí wọ́n ti rí fún ẹnikẹ́ni, títí tí àwọn ọmọ ènìyán yíò fi jí dìde láàrin àwọn òku. \v 10 Nítorínà, wọ́n pa ọ̀rọ̀ náà mọ́ láàrin ara wọn, ṣùgbọ́n wọ́n ń jíròrò láàrin ara wọn nípa ohun tí ó túmọ̀ sí, "jíjí dìde kúrò láàrin àwọn òku" túmọ̀ sí.
\v 9 Bí wọ́n ti ń ti orí òkè sọ̀kalẹ̀, Jésù pàṣẹ fún wọn láti máṣe sọ ohun tí wọ́n ti rí fún ẹnikẹ́ni, títí tí àwọn ọmọ ènìyán yíò fi jí dìde láàrin àwọn òku. \v 10 Nítorínà, wọ́n pa ọ̀rọ̀ náà mọ́ láàrin ara wọn, ṣùgbọ́n wọ́n ń jíròrò láàrin ara wọn nípa ohun tí "jíjí dìde kúrò láàrin àwọn òku" túmọ̀ sí.

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn bi Jésù léèrè pé, "Èése tí àwọn akòwé fi bií léèrè wípé Èlíjà ni ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ wá."? \v 12 Jésù wí fún wọn pé, "Èlíjà ti kọ́kọ́ wá ná láti mún ohungbogbo padàbòsípò.Èsée tí a wá fi kọ̀wé rẹ̀ pé Ọmọ ènìyàn gbọ́dọ́ jìyà ohunpúpọ̀ kí á sì seé bíi ẹni tí kòní láárii? \v 13 Sùgbọ́n èmi wí fún n yín pé Èlíjá ti wá ná, wọ́n sì seé ohungbogbo tí ó wù wọ́n síi, gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ ti wí nípa rẹ̀."
\v 11 Àwọn ọmọ ẹ̀yìn bi Jésù léèrè pé, "Èéṣe tí àwọn akọ̀wé fi ṣọ wípé Èlíjà ni ó gbọ́dọ̀ kọ́kọ́ wá."? \v 12 Jésù wí fún wọn pé, "Èlíjà ti kọ́kọ́ wá ná láti mún ohungbogbo padàbòsípò.Èése tí a wá fi kọ̀wé rẹ̀ pé Ọmọ ènìyàn gbọ́dọ́ jìyà ohunpúpọ̀ kí á sì seé bíi ẹni tí kòní láárii? \v 13 Sùgbọ́n èmi wí fún n yín pé Èlíjá ti wá ná, wọ́n sì seé ohungbogbo tí ó wù wọ́n síi, gẹ́gẹ́ bí ìwé mímọ́ ti wí nípa rẹ̀."