Tue May 14 2019 15:06:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-14 15:06:36 +01:00
parent 02ee88faa5
commit 380282a348
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti iranse gbogbo eniyan."
\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn."

View File

@ -1 +1 @@
\v 36 O mun omo kekere kan O si fii si aarin won. Jesu gbe le owo Re osi wi fun won pe, \v 37 "Enikeni ti o ba gba omode kekere yi ni oruko mi, o gbami pelu, bi enikeni basi gba mi, ko gba emi nikan, sugbon o gba eni ti o ranmi pelu."
\v 36 Ó mún omo kekere kan O si fii si aarin won. Jesu gbe le owo Re osi wi fun won pe, \v 37 "Enikeni ti o ba gba omode kekere yi ni oruko mi, o gbami pelu, bi enikeni basi gba mi, ko gba emi nikan, sugbon o gba eni ti o ranmi pelu."