diff --git a/09/33.txt b/09/33.txt index 381d9d6..d1de337 100644 --- a/09/33.txt +++ b/09/33.txt @@ -1 +1 @@ -\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti iranse gbogbo eniyan." \ No newline at end of file +\v 33 Lẹ́hìn náà ni wọ́n wá sí Kápánámù. Nígbàtí ó sì ti wọ sínú ilé kan, Ó biwọ́n léèrè pé, "Kíni ẹ̀yin n bára yín sọ lójú ọ̀nà.?" \v 34 Wọ́n sì dákẹ́ jẹ́ẹ́. Nítorítí wọ́n ti n se àríyànjiyàn láàrin ara wọn níti ẹnití ó pọ̀jùlọ láàrin wọn. \v 35 Nígbàtí Ó Jókòó, Ó pe àwọn méjìlá sí ọ̀dọ̀ ara rẹ̀ ósì wí fún wọn pé, "bí ẹnikẹ́ni bá fẹ́ se ẹni àkọ́kọ́, Oun ni yíò jẹ́ ẹni ìkẹyìn àti ìránsẹ́ gbogbo ènìyàn." \ No newline at end of file diff --git a/09/36.txt b/09/36.txt index 73bf28b..57953f4 100644 --- a/09/36.txt +++ b/09/36.txt @@ -1 +1 @@ -\v 36 O mun omo kekere kan O si fii si aarin won. Jesu gbe le owo Re osi wi fun won pe, \v 37 "Enikeni ti o ba gba omode kekere yi ni oruko mi, o gbami pelu, bi enikeni basi gba mi, ko gba emi nikan, sugbon o gba eni ti o ranmi pelu." \ No newline at end of file +\v 36 Ó mún omo kekere kan O si fii si aarin won. Jesu gbe le owo Re osi wi fun won pe, \v 37 "Enikeni ti o ba gba omode kekere yi ni oruko mi, o gbami pelu, bi enikeni basi gba mi, ko gba emi nikan, sugbon o gba eni ti o ranmi pelu." \ No newline at end of file