Wed Jun 26 2019 13:56:57 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 13:56:58 -12:00
parent 6d47cae408
commit 31b518157a
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Àwọn tí ó fi oúnjẹ fún àwọn elẹ́dẹ̀ náà sí sálọ, wọ́n sí ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ lárin ìlú àti ní gbogbo agbègbè, àwọn ènìyàn sì jáde láti rí ohun tí ó sẹlẹ̀. \v 15 Àwon ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n sì rí Ọkùnrin ẹlẹ́mìí àìmọ́ náà, èyí tí ó kún fún Lígíónì, ó jóko pẹ̀lú ẹ̀wù lọ́rùn pẹ̀lú ọpọlọ tó yè koro.
\v 14 Àwọn tí ó fi oúnjẹ fún àwọn elẹ́dẹ̀ náà sí sálọ, wọ́n sí ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ lárin ìlú àti ní gbogbo agbègbè, àwọn ènìyàn sì jáde láti rí ohun tí ó sẹlẹ̀. \v 15 Àwon ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n sì rí Ọkùnrin ẹlẹ́mìí àìmọ́ náà, èyí tí ó kún fún Lígíónì, ó jóko pẹ̀lú ẹ̀wù lọ́rùn àti ọpọlọ tó yè koro.

View File

@ -1 +1 @@
\v 16 Àwọn tí ó sì rí ohun tí ó sẹlẹ̀ sí okùnrin ẹlẹ́mì àìmọ́ náà ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ ní kíkún fún wọn, wọ́n sì ròyìn fún wọn nípa ohun tí ó sẹlẹ̀ sí àwon ẹlẹ́dẹ̀. \v 17 Nígbànà ní wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sì ní bẹ̀ pé kó fi agbègbè àwọn sílẹ̀.
\v 16 Àwọn tí ó sì rí ohun tí ó sẹlẹ̀ sí kùnrin ẹlẹ́mì àìmọ́ náà ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ ní kíkún fún wọn, wọ́n sì ròyìn fún wọn nípa ohun tí ó sẹlẹ̀ sí àwon ẹlẹ́dẹ̀. \v 17 Nígbànà ní wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sì ní bẹ̀ pé kó fi agbègbè àwọn sílẹ̀.