Wed Jun 26 2019 13:54:57 GMT-1200 (Dateline Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-26 13:54:58 -12:00
parent 5efb7ca86a
commit 6d47cae408
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 11 Ó sì se, agbo awọn ẹlẹ́dẹ̀ sì jẹun lórí òkè, \v 12 Wọ́n sì bẹ́ẹ̀, wípé, "Rán wa lọ sí inú agbo ẹlẹ́dẹ̀; kí a sì wọ inú wọn lọ." \v 13 Ó sì gbà wọ́n láyè; àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sì jáde, wọ́n sì wọnù àwọn agbo ẹlẹ́dẹ̀ lọ, wọ́n sì sáré sọ̀kalẹ̀ lọ sínú òkun, bí ẹgbẹ̀rún méjì ẹlẹ́dẹ̀ si parun sínú òkun.
\v 11 Ó sì se, agbo àwọn ẹlẹ́dẹ̀ sì jẹun lórí òkè, \v 12 Wọ́n sì bẹ́ẹ̀, wípé, "Rán wa lọ sí inú agbo ẹlẹ́dẹ̀; kí a sì wọ inú wọn lọ." \v 13 Ó sì gbà wọ́n láyè; àwọn ẹ̀mí àìmọ́ náà sì jáde, wọ́n sì wọnù àwọn agbo ẹlẹ́dẹ̀ lọ, wọ́n sì sáré sọ̀kalẹ̀ lọ sínú òkun, bí ẹgbẹ̀rún méjì ẹlẹ́dẹ̀ si parun sínú òkun.

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Àwọn tí ó fi oúnje fún àwọn elẹ́dẹ̀ náà sí sálọ, wọ́n sí ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ lárin ìlú àti ní gbogbo agbègbè, àwọn ènìyàn sì jáde láti rí ohun tí ó sẹlẹ̀. \v 15 Àwon ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n sì rí Ọkùnrin ẹlẹ́mìí àìmọ́ náà, èyí tí ó kún fún Lígíónì, ó jóko pẹ̀lú ẹ̀wù lọ́rùn pẹ̀lú ọpọlọ tó yè koro.
\v 14 Àwọn tí ó fi oúnj fún àwọn elẹ́dẹ̀ náà sí sálọ, wọ́n sí ròyìn ohun tí ó sẹlẹ̀ lárin ìlú àti ní gbogbo agbègbè, àwọn ènìyàn sì jáde láti rí ohun tí ó sẹlẹ̀. \v 15 Àwon ènìyàn sì wá sọ́dọ̀ Jésù, wọ́n sì rí Ọkùnrin ẹlẹ́mìí àìmọ́ náà, èyí tí ó kún fún Lígíónì, ó jóko pẹ̀lú ẹ̀wù lọ́rùn pẹ̀lú ọpọlọ tó yè koro.