Thu May 16 2019 12:05:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:05:35 +01:00
parent 98639de150
commit 2b8152b102
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì ń bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ó sì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, ẹjẹ́ kí á se ibùgbé mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi) \v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì ń bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ó sì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, Ẹ jẹ́ ká kọ́ ilé'gbe mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi)

View File

@ -1 +1 @@
\v 7 Àwọ̀ sánmọ́ sì síjibòwọ́nmọ́lẹ̀. Lọ́gán, ohùn kan jáde wá láti inú àwọ̀ọsánmọ̀n wá wípé, "Èyíyìí ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹ máa gbọ́ tirẹ̀." \v 8 Bí wọ́n ti wò àyíká wọn, wọn kò rí ẹnìkankan pẹ̀lú wọn mọ́, bíkòse Jésù nìkan. \v 7 Àwọ̀ sánmọ́ sì íjibòwọ́nmọ́lẹ̀. Lọ́gán, ohùn kan jáde wá láti inú àwọ̀ọsánmọ̀n wá wípé, "Èyíyìí ni àyànfẹ́ ọmọ mi, ẹ máa gbọ́ tirẹ̀." \v 8 Bí wọ́n ti wò àyíká wọn, wọn kò rí ẹnìkankan pẹ̀lú wọn mọ́, bíkòse Jésù nìkan.