Thu May 16 2019 12:03:34 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-05-16 12:03:35 +01:00
parent e7e88b9fcd
commit 98639de150
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\c 9 \v 1 Jésù sì wi fún wọn pé, "Lóòtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú yín tí ó dúró níhìńyí ní kì yíò rí ikú kí wọ́n tó rí ìjọba ọlọ́run tí yíò dè pẹ̀lú agbára." \v 2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mú Pétérù àti Jákọ́bù àtiJòhánù pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sórí òkè gíga, wọ́n dáwà níbẹ̀. A sì paá láradà níwájú wọn. \v 3 Aṣọ Rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ síí tàn bí i mọ̀nàmọ́ná, ó funfun bí ọṣẹ ìfọṣọ ayé kan ìbá fi fọ̀ ọ́ gbòò, ó funfun ju ohun ìbóṣọ kí ìbósọ nínú ayé lọ.
\c 9 \v 1 Jésù sì wi fún wọn pé, "Lóòtọ́ọ́ ni mo wí fún yín, ọ̀pọ̀lọpọ̀ nínú yín tí ó dúró níhìńyí ní kì yíò rí ikú kí wọ́n tó rí ìjọba ọlọ́run tí yíò dè pẹ̀lú agbára." \v 2 Lẹ́yìn ọjọ́ mẹ́fà, Jésù mú Pétérù àti Jákọ́bù àtiJòhánù pẹ̀lú Rẹ̀ lọ sórí òkè gíga, wọ́n dáwà níbẹ̀. A sì paá láradà níwájú wọn. \v 3 Aṣọ Rẹ̀ bẹ̀rẹ̀ síí tàn bí i mọ̀nàmọ́ná, ó funfun bí ọṣẹ ìfọṣọ ayé kan ìbá fi fọ̀ ọ́ lọ.

View File

@ -1 +1 @@
\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mòósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì n bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ósì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, ẹjẹ́ kí á se ibùgbé mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi)
\v 4 Lẹ́hìn náà, Èlíjà àti Mósè fara hàn wọ́n, wọ́n sì ń bá Jésù sọ̀rọ̀. Pétérù dáhùn ó sì wí fún Jésù pé, \v 5 "Olùkọ́ni, ó dára fún wa láti máa gbé ibíyìí, nítorínà, ẹjẹ́ kí á se ibùgbé mẹ́ta, ọ̀kan fún ọ, ọ̀kan fún Mósè, àti ọ̀kan fún Èlíjà." \v 6 (Nítorí Pétérù kò mọ ohun tí yíò sọ, nítorí ẹ̀rù bà wọ́n gidigidi)