Tue May 11 2021 15:47:40 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
iconcept 2021-05-11 15:47:41 +01:00
commit 1c2feb7498
26 changed files with 52 additions and 2 deletions

1
06/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 6 \v 1 O si jade lo si ilu abinibi re, awon omo eyin Re si te le. \v 2 Nigbati odi ojo Sabati, O nko won ninu sinagogu. Opo eniyan si gbo eko naa, enu si ya won. Won si bere wipe, "nibo ni o ti ri gbogbo eko ti on ko ni yi?" "Iru ogbon wo ni afi fun yi?" "Iru awon ise iyanu wo ni on fi owo re se wonyi?" \v 3 "Se kii se gbenagbena naa ni yi, omo bibi Maria, ati arakunrin Jemisi, ati Jose, ati Juda, ati Simoni? Sebi awon arabirin re ngbe pelu wa?" Inu Jesu si bi won.

1
06/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 4 Jesu si wi fun won pe, "Woli kii sa lai lola, ayafi larin ilu re, ati lodo awon eniyan re, ati ninu ile re." \v 5 Ko si le sise iyanu larin won, O kan gbe owo le awon alaisan die, O si wo won san. \v 6 Enu si yaa nitori aigbagbo won, O si jade lo si awon abule lati ko won.

1
06/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 O si pe awon mejila, O ran won jade ni meji meji, O si fun won ni agbara lori awon emi aimo. \v 8 O wi fun won pe; e ko gbodo mu ohun kohun dani fun irinajo yi, bikose opa itile yin, e kogbodo mu akara tabi gbe apo tabi mu owo sinu igbadi. \v 9 Sugbon, ki won ki o wo bata, ki won ma si mu aso miran dani.

1
06/10.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 10 O si wi fun won pe, "ilekile ti eba wo, nibe niki e duro si digba ti eba kuro ni ilu naa. \v 11 Ti ilu kan ko ba gba yin tabi ti won ko teti si eko yin, nigba ti e ba kuro nibe, ki e si gbon eruku ese yin sibe gege bi eri si won."

1
06/12.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 12 Won si jade lo lati kede pe ki awon eniyan yipada kuro ninu ese won. \v 13 Won le awon emi esu jade, won fi ororo kun awon alaisan won si gba imularada.

1
06/14.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 14 Oba Erodu si gbo, nitori iroyin Jesu tan ka. Awon kan nwipe "Johanu Onitebomi ti ji dide, idi niyi ti ise agbara fi nsele lati owo re. \v 15 Awon miran si wipe "Elija ni." Be ni awon miran si wipe "okan ninu awon woli atijo ni."

1
06/16.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 16 Sugbon nigbati Herodu gbo eyi, o wipe "Johanu ti mo ge ori re, ti ji dide." \v 17 Nitori Herodu ranse lati mu Johanu, o si ju sewon nitori Herodia, aya arakunrin re Filipi ti o yan lale.

1
06/18.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 18 Nitori Johanu ba Herodu wi, "pe ko tona lati yan aya arakunrin re lale." \v 19 Herodia si binu si Johanu, o si n wa ona lati pa a, eyi si nira fun \v 20 nitori Herodu beru Johanu. Ati wipe o mo pe olododo ati eniyan mimo ni, o si pa a mo. Gbigbo oro re ma n bii ninu, sugbon o ma n fi ayo gboo.

1
06/21.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 21 Anfani lati pa a wa nigbati Oba Herodu se ojo ibi, osi se ase fun awon emewa re, awon alase ati awon adari ni ile Galili. \v 22 Omobirin Herodia si wa fi ijo da Herodu ati awon alejo re laraya. Oba Herodu si wipe fun omobirin na pe: "bere ohun kohun ti o ba fe ni owo mi, emi o si fi fun o."

1
06/23.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 23 Herodu si bura fun odomobirin na pe, "ohun kohun ti o ba fe titi de idaji ijoba mi, ni emi o fifun o. \v 24 Omobirin yi si lo bere lowo iya re wipe; "ki ni kin bere?" O si wi fun pe, "bere ori Johanu Onitebomi." \v 25 O si sare pada wa ba oba, o si beere wipe, "Mo fe ori Johanu Onitebomi nisisiyi sinu igba yi."

1
06/26.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 26 Bo tile je wipe eyi ba oba ninu je, ko le sa lai mu ibeere re se nitori ti oti bura fun un ati nitori awon alejo re. \v 27 Oba ran awon emewa re ki won lo be ori Johanu wa. Emewa naa si lo be ori Johanu lati inu ogba ewon wa \v 28 Osi gbe fun odomobirin naa ninu igba, omobirin naa si lo gbe fun iya re. \v 29 Nigbati awon omoleyin re gbo, won lo gbe ara re toku lo si iboji.

1
06/title.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
Maaku Ori Kefa

1
11/01.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\c 11 \v 1 ti won si de Jerusalemu, won sun mo Betifeji ati Betani, ni ori oke olifi, Jesu si ran awon omo eyin re meji jade \v 2 O si wi fun won pe, "e lo si abule ti o koju si wa. Ni kete ti e ba ti wo inu re, e o ri ketekete kan ti a ko gun ri. E tu ki e si mu wa fun mi. \v 3 Ti enikeni ba so fun yin wipe, 'kilode ti en tu?' E da lohun wipe Oluwa nilo re yio si daa pada kankan.

1
11/04.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 5 \v 4 Won si lo, won ri kekete kan ti a so mo enu ona ni ita gbangba ni adugbo, won si tu.\v 5 Awon eniyan kan si duro nibe ti o wi fun won pe, "ki ni eyin n se, ti e n tu ketekete?" \v 6 Won si da won lohun gege bi Jesu ti so fun won, awon eniyan naa si je ki won lo ni ona ti won.

1
11/07.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 7 omo eyin meji naa mu ketekete naa wa sodo Jesu won si te aso won sori re ki Jesu le gun ketekete naa. \v 8 Opo eniyan si te aso won sile ni oju ona, awon miran si te imo ti won ti ge lati inu oko. \v 9 Awon ti o nlo niwaju re ati awon ti o n bo lehin re n kigbe, "Hosana! Ibukun ni eni ti o wa ni oruko Oluwa. \v 10 Ibukun ni fun ijoba baba wa Dafidi ti n bo wa! Hosana ni ibi giga julo."

1
11/11.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 11 Leyin naa ni Jesu wo Jerusalemu, O si wo inu tempili, o wo gbogbo ohun ti o wa ni ayika. Ile si ti su ni akoko naa, O si jade lo si Betani pelu awon omo eyin mejila. \v 12 Ni ojo keji, nigbati won pada de lati Betani, ebi si n paa.

1
11/13.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 13 O si ri igi opoto kan ti o ni ewe ni ookan, O si lo lati wo boya O leri eso ni ori re, ni gba ti o si de idi igi naa, ko ri eso kan lori re bikose ewe, nitori ki n se asiko eso opoto. \v 14 O si soro si, "ko si eniti yio je eso lori re mo." Awon omo eyin re si gbo.

1
11/15.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 15 Won si wa si Jerusalemu, O si wo inu tempili, O si bere si n le awon tin ra tin ta ninu tempili jade. O si da tabili awon tin se pasiparo owo ati ijoko awon tin ta eyele nu. \v 16 Ko gba enikeni laye lati gbe oja tita wonu tempili.

1
11/17.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 17 O si ko won wipe, Se bi ati ko wipe "a o ma pe ile mi ni ile adura fun gbogbo orile ede? Sugbon eti so di ogba awon ole. \v 18 Awon olori alufa ati awon akowe gbo ohun ti o so, won si n wa ona lati pa. Nitori won beru re tori opo ero ti enu ya nitori eko re. \v 19 Nigba ti o di irole, won fi ilu naa sile.

1
11/20.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 20 Bi won se n rin lo ni owuro, won ri igi opoto naa ti o ti gbe de gbongbo re. \v 21 Peteru ranti o si wipe, "Olukoni, wo o! Igi opoto ti efi re ti gbe danu."

1
11/22.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 22 Jesu si dahun wipe, "Eni igbagbo ninu Olorun \v 23 Looto ni mo so fun yin enikeni to ba so fun oke, 'dide gera re so sinu okun,' ti ko si siyemeji ninu okan re sugbon ti o gbagbo pe ohun ti o so yio sele, bee gege ni Olorun yio se.

1
11/24.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 24 Nitorina mo wi fun yin, gbogbo ohun ti eyin ba gbadura ti e si beere fun, e gbagbo pe e ti ri gba, yio si di ti yin. \v 25 Nigbati eyin ba duro lati gbadura, e dari ji eniti o se yin, ki baba yin tin be lorun le dari ese ti yin naa ji yin. \v 26 Sugbon ti eyin ko ba dariji, baba yin tin be ni orun ko ni dariji eyin naa.

1
11/27.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 27 Won tun wa si Jerusalemu lekan sii. Bi Jesu ti n rin lo ninu tempili, awon olu alufa, awon akowe, ati awon agbaagba wa sodo re. \v 28 Won si bere lowo re pe, "labe ase wo ni iwo ti n se awon nkan wonyi, ati wipe tani o fun o lase lati se won?"

1
11/29.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 29 Jesu si dawon lohun wipe, "emi a bere ibere kan lowo yin, e dami lohun emi o si so fun yin nipa ase ti mo fi n se awon nkan wonyi. \v 30 Iribomi ti Johanu, se lati orun wa ni tabi lati owo eniyan? e wi fun mi"

1
11/31.txt Normal file
View File

@ -0,0 +1 @@
\v 31 Won se asaro larin ara won wipe, "ti a ba so wipe, 'lati orun', oun a dahun pe 'kilo de ti e ko fi gba a gbo?' \v 32 Sugbon ti a ba so wipe, 'lati owo eniyan'...." Eru awon eniyan n ba won, nitori gbogbo eniyan ni o daloju pe woli ni Johanu. \v 33 Leyin naa won da Jesu lohun wipe, "awa ko mo." Jesu si wi fun won pe, "Emi naa ko ni so fun yin nipa ase ti mo fi se awon nkan wonyii.

View File

@ -43,7 +43,8 @@
"ALAMU, ESTHER OYELOLA",
"Matthew Oladipupo Aremu",
"Sijuade Caleb Okunade",
"OYEKOLA VICTOR OYEYEMI"
"OYEKOLA VICTOR OYEYEMI",
"Faith Opade"
],
"finished_chunks": [
"10-title",
@ -183,6 +184,30 @@
"05-35",
"05-36",
"05-39",
"05-41"
"05-41",
"06-01",
"06-04",
"06-07",
"06-10",
"06-12",
"06-14",
"06-16",
"06-18",
"06-21",
"06-23",
"06-26",
"11-01",
"11-04",
"11-07",
"11-11",
"11-13",
"11-15",
"11-17",
"11-20",
"11-22",
"11-24",
"11-27",
"11-29",
"11-31"
]
}