Mon Nov 25 2019 04:58:38 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-25 04:58:39 -08:00
parent 4f90f9bfd2
commit 143c699087
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Júdásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwé, àti àwọn àgbà. \v 44 Ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Ẹnikẹ́ni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Júdásì sì dé, lójúkanńà ó tọ Jésù wá ó sì wípé, "Olùko," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.
\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Júdásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwé, àti àwọn àgbà. \v 44 Ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Ẹnikẹ́ni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Júdásì sì dé, lójúkanńà ó tọ Jésù wá ó sì wípé, "Olùkọ́," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.

View File

@ -1 +1 @@
\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára wọn tí ó sún mọ́ wọn yo idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlúfà. \v 48 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó lòdì sí olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbàgbogbo tí mo sì ń kọ́ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ se." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jesu sì fi sílẹ wọ́n sì sáré kúrò.
\v 47 Ṣùgbọ́n ọ̀kan lára àwọn tí ó sún mọ́ wọn yọ idà rẹ̀ ó sì fi gé etí ọmọ-ọ̀dọ̀ olórí àlúfà. \v 48 Jésù sí wí fún wọn pé, "Sé ẹ̀yin jáde wá gẹ́gẹ́ bí ẹni tí ó lòdì sí olè ni, pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀ láti wá mú mi? \v 49 Nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nígbàgbogbo tí mo sì ń kọ́ yín ní témpílì, ẹ̀yin kò mú mi. Ṣùgbọ́n a se èyí kí á le mú ọ̀rọ̀-mímọ́ se." \v 50 gbogbo àwọn tí ó wà pẹ̀lu Jesu sì fi sílẹ wọ́n sì sáré kúrò.

View File

@ -54,7 +54,7 @@
"14-35",
"14-37",
"14-40",
"14-47",
"14-43",
"14-51",
"14-53",
"14-55",