Mon Nov 25 2019 04:56:38 GMT-0800 (Pacific Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-11-25 04:56:39 -08:00
parent 92e65d766e
commit 4f90f9bfd2
1 changed files with 1 additions and 1 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Júdásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwé, àti àwọn àgbà. \v 44 Ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Enikéni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Judasi sì dé, lójúkanńà ó tọ Jesu wá ó sì wípé, "Rabbi," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.
\v 43 Nígbàtí ó sì ń sọ̀rọ̀, Júdásì, ọ̀kan nínú àwọn méjìlá, dé, ọ̀pọ̀ ènìyàn sí wà pẹ̀lú rẹ̀ pẹ̀lú idà àti ọ̀kọ̀, láti ọ̀dọ̀ olórí àlúfà, àwọn akòwé, àti àwọn àgbà. \v 44 Ẹni tí yí ò dà á ti fún wọn ní àmì, wípé, " Ẹnikẹ́ni tí òun bá fi ẹnu kò ní ẹnu, òun ni. Ẹ mú u lọ." \v 45 Nígbàtí Júdásì sì dé, lójúkanńà ó tọ Jésù wá ó sì wípé, "Olùko," ó sì fi ẹnu kò ó ní ẹnu. \v 46 Wọ́n sì mú u.