Thu Jun 27 2019 11:05:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 11:05:11 +01:00
parent 3a120fbce3
commit 01acca7efc
2 changed files with 2 additions and 2 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 19 Wón lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní wájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti fi se ẹlẹ́yà tán, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà wọ́n sì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tó n kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbélèbú Jésù, ọkùnrin tí à n pé orúkọ rẹ̀ ní Símónì ará Kírénì, bàbá Alesándérù àti Rúfọ́sì.
\v 19 Wọ́n lu orì rẹ̀ pẹ̀lú ọ̀pá wọ́n sì tu itọ́ síi lára. Wọ́n kúnlẹ̀ ní iwájú rẹ̀ bíì pé wón júbà rè. \v 20 Nígbàtí wọ́n ti fi se ẹlẹ́yà tán, wọ́n bọ́ asọ ìgúnwà elése àlùkò náà wọ́n sì fi asọ rẹ̀ wọ̀ọ́, wón sì múu lọ láti kàán mọ́ àgbélèbú \v 21 Wọ́n fi ipá mú ẹnìkan tó n kọjá lọ lẹ́bàá ọ̀nà láti gbé àgbélèbú Jésù, ọkùnrin tí à n pé orúkọ rẹ̀ ní Símónì ará Kírénì, bàbá Alesándérù àti Rúfọ́sì.

View File

@ -43,8 +43,8 @@
"15-09",
"15-12",
"15-14",
"15-16",
"15-19",
"15-22",
"15-25",
"15-29",
"15-31",