Thu Jun 27 2019 11:03:09 GMT+0100 (W. Central Africa Standard Time)

This commit is contained in:
tsDesktop 2019-06-27 11:03:11 +01:00
parent b51cfc9d64
commit 3a120fbce3
3 changed files with 3 additions and 3 deletions

View File

@ -1 +1 @@
\v 9 Pílátù dáwọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ́ kí èmi fi Ọba àwọn Júù lé e yín lọ́wọ́ bi?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfáà fi Jésù lé òun lọ́wọ́ nítorí owú ni \v 11 Ṣùgbọ́n àwọn olórí àlùfáà ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kí ó fi sílẹ̀ ẹ̀wẹ̀.
\v 9 Pílátù dáwọn lóhùn wípé, "Ǹjẹ́ ẹ̀yin fẹ́ kí èmi fi Ọba àwọn Júù lé e yín lọ́wọ́ bi?" \v 10 Nítorí ó mọ̀ pé àwọn olórí àlùfáà fi Jésù lé òun lọ́wọ́ nítorí owú ni \v 11 Ṣùgbọ́n àwọn olórí àlùfáà ru àwọn èrò sókè láti pariwo pé Baraba ni kí ó fi sílẹ̀ (ẹ̀wẹ̀).

View File

@ -1 +1 @@
\v 14 Pílátù sì wí fún wọn, "Kíni àìda tó se?" Sùgbọ́n wọ́n tún pariwo sókè síi, "Kàn-án mọ́ àgbélèbú." \v 15 Pílátù fẹ́ tẹ́ àwọn èrò náà lọ́rùn, nítorínà, ó fi Bárábà sílẹ̀ fún wọn. Ósì naa Jésù, lẹ́yìn náà ó fi lé wọn lọ́wọ́ láti kàán mọ́ àgbélèbú.
\v 14 Pílátù sì wí fún wọn, "Kíni àìda tó se?" Sùgbọ́n wọ́n tún pariwo sókè síi, "Kàn-án mọ́ àgbélèbú." \v 15 Pílátù fẹ́ tẹ́ àwọn èrò náà lọ́rùn, nítorínà, ó fi Bárábà sílẹ̀ fún wọn. Ósì naa Jésù, lẹ́yìn náà ó fi lé wọn lọ́wọ́ láti kà-án mọ́ àgbélèbú.

View File

@ -40,9 +40,9 @@
"15-01",
"15-04",
"15-06",
"15-09",
"15-12",
"15-14",
"15-16",
"15-19",
"15-22",
"15-25",