yo_php_text_ulb/01/09.txt

1 line
401 B
Plaintext

\v 9 Àdúrà mi nì yí: pé kí ìfẹ́ yín le máa gbilẹ̀ síi nínú ìmọ̀ àti gbogbo òye. \v 10 Mò ń gbàdúrà yí kí ẹ̀yin kí ó le ṣe àgbéyẹ̀wò ohun tí ó yege, kí ẹ sì wà ní àìní àbùkù kankan lọ́jọ́ Krístì. \v 11 Mo gbàdúrà pé kí á fi èso òdodo tí ó wá láti ipasẹ̀ Jésù Krístì kún un yín, fún ògo àti ìyìn Ọlọ́run.