yo_php_text_ulb/03/20.txt

1 line
358 B
Plaintext

\v 20 Ṣùgbọ́n ìlú ìbílẹ̀ wa ń bẹ ní ọ̀run, láti ibití àwa ti ń retí Olùgbàlà kan, Jésù Krístì Olúwa. \v 21 Yíò pa àwọn ara yẹpẹrẹ wa yí dà si èyí tí a dá ní ìrísí ara ògo tirẹ̀, èyí tí a dá nípa ipá agbára Òun tìkara Rẹ̀ láti mú kí ohun gbogbo kí ó wà lábẹ́ ìsàkóso Rẹ̀.