yo_php_text_ulb/02/03.txt

1 line
290 B
Plaintext

\v 3 Ẹ máṣe ṣe ohunkóhun nínú ìmọtara-ẹni-nìkan tàbi ìgbéraga. Kàkà bẹ́ẹ̀ nínú ìrẹ̀lẹ̀ ẹ ka elòmíràn kún ju ara yín lọ. \v 4 Kí olúkúlùkù yín máa tán àìní àwọn ẹlòmíràn pẹ̀lú, kí ó má sì ṣe tán ti ara rẹ̀ nìkan.