1 line
413 B
Plaintext
1 line
413 B
Plaintext
\v 12 Ǹjẹ́, ará mi olùfẹ́, gẹ́gẹ́ bí ẹ ṣe má n gbọ́ràn nígbà gbogbo, kìí ṣe nígbà tí mo wà pẹ̀lú yín nìkan ṣùgbọ́n nígbà tí èmi kò sí nítòsí, ẹ jára mọ́ iṣẹ́ ìgbàlà yín pẹ̀lú ẹ̀rù àri ìwárìrì. \v 13 Nítorí Ọlọ́run ló ń mú kí ó wù yín láti ṣe ìfẹ́ Rẹ̀ tí ó sì tún n ró yín lágbára láti ṣe é. |